Patrick Seubo Koshoni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Patrick Koshoni)
Jump to navigation Jump to search
Chief of Naval Staff
In office
1986–1990
AsíwájúRear Adm. A. Aikhomu
Arọ́pòVice Adm. M. Nyako
Federal Minister of Employment, Labour and Productivity
In office
1985–1986
Federal Minister of Health
In office
December 1983 – August 1985
AsíwájúD.C Ugwu
Arọ́pòOlikoye Ransome-Kuti
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1943-04-17)Oṣù Kẹrin 17, 1943
Lagos
AláìsíJanuary 25, 2020(2020-01-25) (ọmọ ọdún 76)
Alma materSt Finbarr's College
National Defence Academy
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/serviceBadge of the Nigerian Navy.svg Nigerian Navy
Years of service1962-1990
RankVice Admiral

Patrick Seubo Koshoni tàbí Patrick Sẹ́húbò Koshoni tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1943 tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 2020 (April 17, 1943- 25 January, 2020) jẹ́ ajagun-fẹ̀yntì orí omi Nigerian Navy Vice Admiral,[1] ọ̀gágun yányán Chief of Naval Staff àti mínísítà-ana fún ìlera nígbà ìṣèjọba ológun Ààrẹ Muhammadu Buhari.[2] [3] Nígbà ìṣèjọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà-ana fún ètò ìlera, ó gbìyànjú láti ṣe ìdásẹ̀lé ètò Máàdámidófò lórí ìlera láìsí owó sísan kalẹ̀

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Business Report | Get The Latest South African Business News". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-31. 
  2. Francis Arthur Nzeribe (1985). Nigeria, another hope betrayed: the second comìing of the Nigerian military. Kilimanjaro. p. 117. https://books.google.com/books?ei=A5IeTJX6OOSKnwf4_YXNCw&ct=result&id=kXMuAQAAIAAJ&dq=Patrick+Koshoni+health&q=Patrick+Koshoni#search_anchor. Retrieved 2010-06-20. 
  3. "KOSHONI, Vice-Admiral Patrick Seubo (rtd.)". Biographical Legacy and Research Foundation. 2017-03-02. Retrieved 2020-02-02.