Paul Adefarasin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Paul Adefarasin
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kínní 1963 (1963-01-25) (ọmọ ọdún 60)
Nàìjíríà
IbùgbéLagos, Nigeria
Iṣẹ́Minister, televangelist
TitlePastor
Olólùfẹ́Ifeanyi Adefarasin
Àwọn ọmọmeta
Parent(s)

Paul Adefarasin ni a bi ojo karùnlelọgún Oṣu Kini Ọdun 1963 jẹ iranṣẹ Kristiẹni ati olukọ tẹlifisiọnu. Oun ni oludari House On The Rock Church. House on the Rock church je olugbalejo "The Experience" Orin ihinrere [1][2][3]

Ibere Aye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Paul Adefarasin ni abi ni 25 osu Kini Ọdun 1963 si Joseph Adefarasin. Adajọ ile-ẹjọ giga ti orilẹ-ede Naijiria lati ilu Ìjẹ̀bú ode, ati Hilda Adefarasin ti oje Olugbeja ẹtọ awọn obinrin lati ilu ẹ̀kọ́. Paul Adefarasin dàgbà ni Nigeria ati orile-ede Amẹrika [1][2][3]

Ọmọ-iṣẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adefarasin lọ si Ile-iwe St Saviour ni Ikoyi ati Ile-ẹkọ Igbobi niYaba, ni Èkó. Oka iwe ni unifasiti miami ibi tí ó gba Apon tí fàáji. O ṣe adaṣe ni Florida ṣaaju ki o to pada si orilẹ-ede Naijiria .[4][5] O kẹkọ ni International Bible Institute of London nibi ti o ti gba Iwe-ẹkọ kan ni Ile-iṣẹ Kristiẹni.

Atẹjade Iwe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adefarasin ti kọwe, iwe ti otiko ju 20 lo awọn iwe kekere Christian iwuri ati orisun iwuri fún ọpọlọpọ.distributors.[1][2][3]

Igbesi aye ara ẹni[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni Oṣu Keje 1995, Adefarasin fẹ Ifeanyi Adefarasin, ayaba ẹwa tẹlẹ.[6] Won ni omo Meta[7]

  1. 1.0 1.1 1.2 "Home - The Experience Lagos 2016 Revealing Jesus". The Experience Lagos (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 28 February 2019. Retrieved 2016-12-03. 
  2. 2.0 2.1 2.2 Nsehe, Mfonobong (2011-06-22). "Hey! I'm A Billionaire, Nigerian Pastor Cries Out" (in en). Forbes. https://www.forbes.com/sites/mfonobongnsehe/2011/06/22/hey-im-a-billionaire-nigerian-pastor-cries-out/#43c6e02e5e2f. 
  3. 3.0 3.1 3.2 "Inside Pastor Paul Adefarasin’s N50b House On The Rock Church" (in en-US). Encomium Magazine. 2014-08-27. http://encomium.ng/inside-pastor-paul-adefarasins-n50b-house-on-the-rock-church/. 
  4. Pastor Paul Adefarasin builds Multibillion Naira retirement home in Banana. Thisday live. Archived from the original on 15 December 2019. https://web.archive.org/web/20191215231451/https://www.thisdaylive.com/index.php/2017/07/09/pastor-paul-adefarasin-builds-multi-billion-naira-retirement-home-in-banana/amp/. Retrieved August 20, 2018. 
  5. Abiola Salami (2012). Get Mad! (You Can Make a Difference). AuthorHouse. p. 10. ISBN 9781468554557. https://books.google.com/books?id=0WdawlTJJiAC&pg=PA10&dq=. 
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named BP-20160906
  7. "THE LOVE STORY OF PASTOR PAUL ADEFARASIN & WIFE REVEALED". CityPeople. February 18, 2018. http://www.citypeopleonline.com/love-story-pastor-paul-adefarasin-wife-revealed/. Retrieved August 20, 2018.