Paul Kehinde

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Paul Kehinde
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí(1988-07-07)Oṣù Keje 7, 1988
Lagos, Nigeria
Ọjọ́aláìsíNovember 18, 2021(2021-11-18) (ọmọ ọdún 33)
Lagos, Nigeria
Weight60 kg (130 lb)
Sport
Erẹ́ìdárayáPowerlifting
Event(s)65 kg
Updated on 10 April 2018.

Paul Kehinde (tí wọ́n bí ní 7 July 1988 – tó sì kú ní 18 November 2021) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó fìgbà kan jẹ́ eléré-ìdárayá tó máa ń gbé nǹkan tó wúwo.[1] Ìlú Epe, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Nàìjíríà ni wọ́n bi sí. Ó parí kíláàsì ti àwọn ọkùnrin ti 65 kg àti ti 72 kg. Ní 2014 Commonwealth Games[2] ó parí ìdíje àwọn ọkùnrin fún 72 kg, níbi ayẹyẹ náà, níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ oníwárà.[3] Kehinde kú ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2021 ní Eko, lẹ́yìn àìsàn ráńpẹ́ kan.[4][5]

  • Àwọn àṣeyọrí rẹ̀: [6]
  • 2011 – World Championships Silver medalist
  • 2014 – Commonwealth Games Gold medalist
  • 2015 – Malaysia World Cup Gold medalist
  • 2015 – All Africa Games Gold medalist setting an African Record of 214 kg.
  • 2016 – Rio Paralympics- Broke the World Record twice with lifts of 218 kg & 220 kg
  • 2017 – Mexico World Championships Gold medalist with another World Record lift of 220.5 kg.
  • 2018 – World Para-Power lifting Championships, Fazza, Dubia. Gold medal with Record breaking lift of 221 kg .
  • 2018 – Commonwealth Games, Gold Coast, Australia. Silver medalist in +65 kg Para-Power lifting
  • 2018 August – African Para-Power lifting Championships +65 kg Gold medalist
  • 2018 December – Nigerian National Sports Festival +65 kg Silver medalist.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Glasgow 2014 profile". Retrieved 11 October 2014. 
  2. Salman, Ganiyu (3 August 2014). "Nigeria grabs 4 gold in powerlifting". Nigerian Tribune. http://tribune.com.ng/news/sports/item/12413-glasgow-2014-nigeria-grabs-4-gold-in-powerlifting/12413-glasgow-2014-nigeria-grabs-4-gold-in-powerlifting. 
  3. Adedeji, Lekan (10 September 2014). "Powerlifters Not Encouraged - Kehinde". Sports Day (Africa). Archived from the original on 16 October 2014. https://web.archive.org/web/20141016184546/http://www.sportsdayonline.com/news.aspx?lb_newsid=9169#sthash.MsixD1tY.dpbs. 
  4. "Paul Kehinde death: Nigeria powerlifting Paralympics gold medallist don die" (in pcm). BBC News Pidgin. 19 November 2021. https://www.bbc.com/pidgin/tori-59346398. 
  5. Mackay, Duncan (19 November 2021). "Paralympic gold medallist dies five weeks after being banned by IPC for drugs". InsideTheGames.biz. https://www.insidethegames.biz/articles/1115685/paralympic-champion-dies-following-ban. 
  6. "Redirect Notice". www.punchng.com. 19 November 2021. Retrieved 2021-11-20.