Ìṣèlú ilẹ̀ Bòtswánà
Ìṣèlú ilẹ̀ Bòtswánà je ti orile-ede Bòtswánà. Iselu ni Botswana unwaye labe eto orile-ede olominira oloselu asoju, nibi ti Ààrẹ ilẹ̀ Bòtswánà ti je olori orile-ede ati olori ijoba, ati labe sistemu egbe oloselu pupo. Agba apase wa lowo ijobat. Agbara Asofin wa lowo ijoba ati Iléaṣòfin ilẹ̀ Bòtswánà. Idiboyan aipe, ikewa iru re, waye ni ojo 16 Osu Kewa 2009.
Lati igba ilominira, oselu ni Botswana ti je gigaba latowo Egbe Oloselu Botswana. Adajo ni ilominira latodo apase ati asofin. Gege bi Isekedere Akariaye se so, Botswana ni orile-ede Afrika to ni iwa ibaje to din julo, be sini ipo re sunmo Portugal ato Korea Guusu.[1] Nevertheless the country is considered to have the most secretive public institutions.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Transparency International 2008 Corruption Perception Index 2008 Archived 2012-11-27 at the Wayback Machine.. Retrieved 7-23-09.
- ↑ Glenda Daniels (2011-11-11) Botswana, Southern Africa's most secretive state. Mail & Guardian. mg.co.za