Ìgbà Ààrẹ Umaru Musa Yar'Adua
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Presidency of Umaru Musa Yar'Adua)
Ìgbà Ààrẹ Umaru Musa Yar'Adua bere ni 29 May, 2007 leyin ayeye ibura gege bi Aare orile-ede Naijiria ketala. Ki Yar'Adua o to di Aare o ti koko je Gomina Ipinle Katsina lati 1999 de 2007. Ninu idiboyan to waye ni April 21, 2007 Yar'Adua lo bori pelu ibo 24.6 legbegberun to je 70% awon ibo didi si 6.6 legbegberun ti Muhammadu Buhari to je olutako re julo. Sibesibe awon olutako oniselu pe idiboyan ohun ni ojoro won si bere fun ifagile re.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Bio [1]