President Kuti

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

President Kuti jẹ́ fíìmù ilẹ̀ Naijiria tí Ibrahim Yekini gbé jáde. Azeazat Sorunmu ló kọ ọ́, olùdarí fíìmù náà sì jẹ́ Tope Adebayo àti Ibrahim Yekini. Wọ́n ṣàgbéjáde President Kuti ní 14 July 2021.[1]

Àwọn akópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ibrahim Yekini
  • Bimpe Oyebade
  • Odunlade Adekola bí i Ayomide
  • Afeez Abiodun bí i Baba Afusa
  • Adeyemi Adebisi bí i Manager
  • Light Aboluwodi bí i Onibara
  • Omolara Adebayo bí i Lara
  • Poopola Adebimpe bí i Omo olona
  • Seilat Adebowale bí i Alagbo
  • Olaniyan Adenike bí i Receptionist
  • Aderoju Adeyemi bí i Alagbo
  • Janet Ajibawo bí i Olosho
  • Kola Ajeyemi bí i Alagbo
  • Adewale Ajose bí i Bureau de change
  • Yusuf Akintude bí i Alagbole
  • Kemi Apesin bí i Alagbo
  • Deola Ayoade bí i Alagbo
  • Mustapha Abiola bí i Mopol Boyscout
  • Fathia Balogun bí i Kobewude

Ìsọniṣókí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

President Kuti ni alákòóso àwọn ọmọ-ìta, tí gbogbo ènìyàn bọ̀wọ̀ fún, tí wọ́n sì bẹ̀rù; ó dojú kọ ìkọlù láti ọ̀dọ̀ àwọn ẹgbẹ́ olórogún rẹ̀, tí ó ti ń ṣẹ́gun ní gbogbo ìgbà.[2]

Ìgbàwọlé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Láàárín ọ̀sẹ̀ méjì tí wọ́n gbé fíìmù yìí jáde, mílíọ́ọ̀nù méjì ènìyàn ló wò ó lórí YouTube.[3][4]

Àmì-ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fíìmù yìí gba àmì-ẹ̀yẹ fíìmù abínibí tó ó dára jù lọ ní ọdún náà, ní City People Movie Awards.[5]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Online, Tribune (2021-09-19). "President Kuti movie hits over 2million views on YouTube in two weeks". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-30. 
  2. Online, Tribune (2021-09-19). "President Kuti movie hits over 2million views on YouTube in two weeks". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-30. 
  3. Online, Tribune (2021-09-19). "President Kuti movie hits over 2million views on YouTube in two weeks". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-30. 
  4. ""President Kuti" hits over 2 million views in 2 weeks - Yekini Bakare". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-28. Retrieved 2022-07-30. 
  5. Reporter (2021-08-30). "Winners Emerge @ 2021 City People Movie Awards In Abeokuta". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-30.