Wikipedia:Abẹ́ igi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Ìlà 645: Ìlà 645:


:Congratulations to the elected and selected members of the drafting committee, they are all welcome on board. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 10:59, 3 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)
:Congratulations to the elected and selected members of the drafting committee, they are all welcome on board. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 10:59, 3 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)

==Ìjábọ̀ Ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians User Group fún ọdún 2021-2022==
Ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians User Group ń fi akókò yí kéde rẹ̀ fún gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ ati àwọn aláfikún sí ọpọ́n ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Yorùbá Wikipedia wípé èsì tabí àbọ̀ àwọn iṣẹ́ àkànṣe ọlọ́kan-ò-jọ̀kan tí a ti gbé ṣe láàrín ọdún 2021 ti wà ní akọsílẹ̀ báyí fún àgbéyẹwò yín, kí ẹ sì lè mọ bí ẹgbẹ́ náà ti ń sapá láti mú ìdàgbà-sókè bá ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia èdè Yorùbá àti gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ aláfikún Yorùbá Wikipedia lápapọ̀ ṣe ń kópa ribi ribi sí.
Ẹ lè ìtàkùn ìsàlẹ̀ yí láti kà nípa rẹ̀.
https://meta.wikimedia.org/wiki/Yoruba_Wikimedians_User_Group/2021_Report
Ẹ ṣeun [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 18:06, 7 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)

Àtúnyẹ̀wò ní 18:06, 7 Oṣù Kọkànlá 2021

No one needs free knowledge in Esperanto

There is a current discussion on German Wikipedia on a decision of Asaf Bartov, Head of WMF Grants and Global South Partnerships, Wikimedia Foundation, who rejected a request for funding a proposal from wikipedians from eowiki one year ago with the explanation the existence, cultivation, and growth of the Esperanto Wikipedia does not advance our educational mission. No one needs free knowledge in Esperanto. On meta there has also started a discussion about that decision. --Holder (ọ̀rọ̀) 10:58, 5 Oṣù Kàrún 2014 (UTC)[ìdáhùn]

Help for translate

Hello and sorry for writing in English. Can anyone help me translate a small article (2 paragraphs) from English to your language and create the article in your wiki? Please, fell free to answer in my talk page in your wiki anytime. Thanks! Xaris333 (ọ̀rọ̀) 00:25, 13 Oṣù Kẹjọ 2014 (UTC)[ìdáhùn]

Monuments of Spain Challenge

Excuse me for not speaking LANGUAGE yet.

Wikimedia España invites you to join the Monuments of Spain Challenge. And what’s that? It’s a contest. You have to edit, translate or expand articles about the Spanish monuments and you will be granted points. So you’re not just writing about wonderful buildings: you can get prizes!

The time of the contest will include all October and any information you may need is right here.

Join in and good luck!

PS: We would be grateful if you could translate this note into LANGUAGE.

B25es (ọ̀rọ̀) 14:14, 28 Oṣù Kẹ̀sán 2014 (UTC) on behalf of Wikimedia España.[ìdáhùn]

Hello, Dear wikipedians. I invite you to edit and improve this article and to add information about your and other country.--Kaiyr (ọ̀rọ̀) 13:43, 31 Oṣù Kẹ̀wá 2014 (UTC)[ìdáhùn]

Content Translation beta feature is now available

Hello, Content Translation has now been enabled as an opt-in beta feature on this Wikipedia. To start translating, enable the beta feature and go to Special:ContentTranslation or to your contributions page and create a new translation by selecting the source language, the article name and target language. If the article already exists then a warning will be displayed. After you translate the article, you can publish it directly as a new page on the Wikipedia. In case the article gets created by another user while you were translating, you will see an option to save the newly published translation under your user namespace. The number of published pages can be seen on the Content Translation stats page.

Since, this is the first time we have installed the tool on this Wikipedia, there are chances that there may be some problems or service disruptions which we are not yet aware of. We will be monitoring the usage to check for any failures or issues, but please do let us know on the Content Translation talk page or through Phabricator if you spot any problems that prevent you from using the tool. For more information, please read about how to use the tool. You can also view a short screencast on how to use Content Translation. My apologies for writing this announcement only in English. Please feel free to translate this message for wider distribution. Thank you. --KartikMistry (ọ̀rọ̀) 16:31, 21 Oṣù Kàrún 2015 (UTC)[ìdáhùn]

Galicia 20 - 20 Challenge

Wikipedia:Galicia 20 - 20 Challenge is a public writing competition which will improve and translate this list of 20 really important articles into as many languages as possible. Everybody can help in any language to collaborate on writing and/or translating articles related to Galicia. To participate you just need to sign up here. Thank you very much.--Breogan2008 (ọ̀rọ̀) 10:18, 9 Oṣù Kẹfà 2015 (UTC)[ìdáhùn]

New notification when a page is connected to Wikidata

Hello all,

(Please help translate to your language)

The Wikidata development team is about to deploy a new feature on all Wikipedias. It is a new type of notification (via Echo, the notification system you see at the top right of your wiki when you are logged in), that will inform the creator of a page, when this page is connected to a Wikidata item.

You may know that Wikidata provides a centralized system for all the interwikilinks. When a new page is created, it should be connected to the corresponding Wikidata item, by modifying this Wikidata item. With this new notification, editors creating pages will be informed when another editor connects this page to Wikidata.

This feature will be deployed on May 30th on all the Wikipedias, excepting English, French and German. This feature will be disable by default for existing editors, and enabled by default for new editors.

This is the first step of the deployments, the Wikipedias and other Wikimedia projects will follow in the next months.

If you have any question, suggestion, please let me know by pinging me. You can also follow and leave a comment on the Phabricator ticket.

Thanks go to Matěj Suchánek who developed this feature!

Thank you! Lea Lacroix (WMDE) (talk)

Wikidata changes now also appear in enhanced recent changes

Hello, and sorry to write this message in English. You can help translating it.

Starting from today, you will be able to display Wikidata changes in both modes of the recent changes and the watchlist.

Read and translate the full message

Thank you! Lea Lacroix (WMDE) 08:33, 29 Oṣù Kẹfà 2017 (UTC)[ìdáhùn]

(wrong target page? you can fix it here)

Improved search in deleted pages archive

Please help translate to your language

During Wikimedia Hackathon 2016, the Discovery team worked on one of the items on the 2015 community wishlist, namely enabling searching the archive of deleted pages. This feature is now ready for production deployment, and will be enabled on all wikis, except Wikidata.

Right now, the feature is behind a feature flag - to use it on your wiki, please go to the Special:Undelete page, and add &fuzzy=1 to the URL, like this: https://test.wikipedia.org/w/index.php?title=Special%3AUndelete&fuzzy=1. Then search for the pages you're interested in. There should be more results than before, due to using ElasticSearch indexing (via the CirrusSearch extension).

We plan to enable this improved search by default on all wikis soon (around August 1, 2017). If you have any objections to this - please raise them with the Discovery team via email or on this announcement's discussion page. Like most Mediawiki configuration parameters, the functionality can be configured per wiki. Once the improved search becomes the default, you can still access the old mode using &fuzzy=0 in the URL, like this: https://test.wikipedia.org/w/index.php?title=Special%3AUndelete&fuzzy=0

Please note that since Special:Undelete is an admin-only feature, this search capability is also only accessible to wiki admins.

Thank you! CKoerner (WMF) (talk) 18:39, 25 Oṣù Keje 2017 (UTC)[ìdáhùn]

presenting the project Wikipedia Cultural Diversity Observatory and asking for a vounteer in Yorùbá Wikipedia

Hello everyone, My name is Marc Miquel and I am a researcher from Barcelona (Universitat Pompeu Fabra). While I was doing my PhD I studied whether an identity-based motivation could be important for editor participation and I analyzed content representing the editors' cultural context in 40 Wikipedia language editions. Few months later, I propose creating the Wikipedia Cultural Diversity Observatory in order to raise awareness on Wikipedia’s current state of cultural diversity, providing datasets, visualizations and statistics, and pointing out solutions to improve intercultural coverage.

I am presenting this project to a grant and I expect that the site becomes a useful tool to help communities create more multicultural encyclopaedias and bridge the content culture gap that exists across language editions (one particular type of systemic bias). For instance, this would help spreading cultural content local to Yorùbá Wikipedia into the rest of Wikipedia language editions, and viceversa, make Yorùbá Wikipedia much more multicultural. Here is the link of the project proposal: https://meta.wikimedia.org/wiki/Grants:Project/Wikipedia_Cultural_Diversity_Observatory_(WCDO)

I am searching for a volunteer in each language community: I still need one for the Yorùbá Wikipedia. If you feel like it, you can contact me at: marcmiquel *at* gmail.com I need a contact in your every community who can (1) check the quality of the cultural context article list I generate to be imported-exported to other language editions, (2) test the interface/data visualizations in their language, and (3) communicate the existance of the tool/site when ready to the language community and especially to those editors involved in projects which could use it or be aligned with it. Communicating it might not be a lot of work, but it will surely have a greater impact if done in native language! :). If you like the project, I'd ask you to endorse it in the page I provided. In any case, I will appreciate any feedback, comments,... Thanks in advance for your time! Best regards, --Marcmiquel (ọ̀rọ̀) 15:06, 10 Oṣù Kẹ̀wá 2017 (UTC) Universitat Pompeu Fabra, Barcelona[ìdáhùn]

Galicia 15 - 15 Challenge

Wikipedia:Galicia 15 - 15 Challenge is a public writing competition which will improve improve and translate this list of 15 really important articles into as many languages as possible. Everybody can help in any language to collaborate on writing and/or translating articles related to Galicia. To participate you just need to sign up here. Thank you very much.--Breogan2008 (ọ̀rọ̀) 14:43, 12 Oṣù Kẹta 2018 (UTC)[ìdáhùn]

Time to bring embedded maps (‘mapframe’) to most Wikipedias

CKoerner (WMF) (talk) 21:38, 24 Oṣù Kẹrin 2018 (UTC)[ìdáhùn]

Update on page issues on mobile web

CKoerner (WMF) (talk) 20:58, 12 Oṣù Kẹfà 2018 (UTC)[ìdáhùn]


Òfin ètò id̀ib̀ò ní Yòrùbá Wikipedia

Èyí jẹ́ ìjíròrò tí ó ti parí. Jọ̀wọ́ máṣe àtúnṣe kankan si. o lè ṣe àfikún rẹ sí ọ̀rọ̀ ìjíròrò yìí

Èsì ìjíròrò yí ni: Ẹnikẹ́ni tí kò kìí ṣe olóòtú Yorùbá Wikipedia kò lẹ́tọ́ àti dásì ètò ìdìbò Yorùbá Wikipedia. T CellsTalk 09:56, 4 Oṣù Kẹrin 2020 (UTC)[ìdáhùn]


Ako fe ki enikeni ti ko ba n se atunse si ayoka tabi ko ayoka ni Wikipedia ti ede Yoruba dede dasi eto idibo wa rara. Enikeni ti o ba fe dasi eto idibo wa gbodo ti se atunse ti o le ni igba. Onise naa si ti gbodo lo to osu meta ni Yoruba Wikipedia.

Ijomitoro yii maa wa ni sisi sile fun ojo meje ki o to di pipade. Fi onte te ofin yii ti o ba fowo si

Mo fowo si

  1. Mo fowo si. Eni ti ko se nibi pepe ko le je nibi Pepe. T Cells (talk · contribs · email) 08:44, 17 Oṣù Keje 2018 (UTC)[ìdáhùn]
  2. Mo fowo si Agbalagba (ọ̀rọ̀) 07:01, 19 Oṣù Keje 2018 (UTC)
  3. Mo f'ọwọ sì Adefanike (ọ̀rọ̀) 11:42, 19 Oṣù Keje 2018 (UTC)[ìdáhùn]

Emi o fowo so


' Ó di òfin'.T CellsTalk 09:46, 4 Oṣù Kẹrin 2020 (UTC)[ìdáhùn]


Ìjíròrò tí òkè yìí ti parí. Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ ṣe oun kóun lóri rẹ̀.

Enabling a helpful feature for Template editors

CKoerner (WMF) (talk) 21:28, 6 Oṣù Kẹjọ 2018 (UTC)[ìdáhùn]

Wikidata Bridge: edit Wikidata’s data from Wikipedia infoboxes

Wikipedia Asian Month 2019

Please help translate to your language

Wikipedia Asian Month is back! We wish you all the best of luck for the contest. The basic guidelines of the contest can be found on your local page of Wikipedia Asian Month. For more information, refer to our Meta page for organizers.

Looking forward to meet the next ambassadors for Wikipedia Asian Month 2019!

For additional support for organizing offline event, contact our international team on wiki or on email. We would appreciate the translation of this message in the local language by volunteer translators. Thank you!

Wikipedia Asian Month International Team.

MediaWiki message delivery (ọ̀rọ̀) 16:57, 31 Oṣù Kẹ̀wá 2019 (UTC)[ìdáhùn]

Extension of Wikipedia Asian Month contest

In consideration of a week-long internet block in Iran, Wikipedia Asian Month 2019 contest has been extended for a week past November. The articles submitted till 7th December 2019, 23:59 UTC will be accepted by the fountain tools of the participating wikis.

Please help us translate and spread this message in your local language.

Wikipedia Asian Month International Team

--MediaWiki message delivery (ọ̀rọ̀) 14:16, 27 Oṣù Kọkànlá 2019 (UTC)[ìdáhùn]

Wiki Loves Folklore

Hello Folks,

Wiki Loves Love is back again in 2020 iteration as Wiki Loves Folklore from 1 February, 2020 - 29 February, 2020. Join us to celebrate the local cultural heritage of your region with the theme of folklore in the international photography contest at Wikimedia Commons. Images, videos and audios representing different forms of folk cultures and new forms of heritage that haven’t otherwise been documented so far are welcome submissions in Wiki Loves Folklore. Learn more about the contest at Meta-Wiki and Commons.

Kind regards,
Wiki Loves Folklore International Team
— Tulsi Bhagat (contribs | talk)
sent using MediaWiki message delivery (ọ̀rọ̀) 06:15, 18 Oṣù Kínní 2020 (UTC)
[ìdáhùn]

Ìjíròrò nípa irinṣẹ́ "Rollback" àti "Account creator User right

Ìtọrọ fún ìlò agbára Bóòtì

Wikiversity Yoruba Project

I want to aware the omo oduduwa(Yoruba people) about the new project Wikiversity Yoruba. It is a very good project and i ensure you all should support and help in developing it like how we made it possible for Wikipedia Yoruba. Mò bèbè ka fi owo sowopo ka gbe yoruba lo soke pẹlu idasile Wikiversity ti ede abinibi wa.

See at : meta:Requests for new languages/Wikiversity Yoruba ọmọ oduduwa,Tbiw (ọ̀rọ̀) 21:39, 26 Oṣù Kẹjọ 2020 (UTC)[ìdáhùn]

Global bot policy proposal: invitation to a Meta discussion


Join the conversation on the Universal Code of Conduct!

Greetings / Mo kí gbogbo yín!

After about 3 years of rigorous discussions aimed at shaping the Wikimedia 2030 strategy, the Wikimedia community has come up with ten (10) solid recommendations that would guide our actions from now on in this movement. One very important recommendation in the line-up is to “Provide for Safety and Inclusion” and a major action point in this recommendation is to create a universal code of conduct, which would be designed and implemented in conjunction with our communities across the globe.

The universal code of conduct would be a movement-wide policy which seeks to ensure the existence of a universal baseline of acceptable behaviour for everyone participating in our movement, in order to minimize incidents of harassment, bullying, discrimination or even disenfranchisement. This is even more important for much smaller Wikipedia languages like the Yoruba Wikipedia, where policies like this do not already exist. A first draft of the Universal Code of Conduct was concluded in October 2020.

As a global movement, we aim to further develop and enforce this very important blueprint through an inclusive process, with respect to local contexts and existing structures. Hence, we would like to invite the Yoruba Wikipedia community to discuss the different ways that you think that the Universal Code of Conduct should be implemented on this Wikipedia and across the global movement.

You can share your initial thoughts directly under this message, or on the UCoC meta talk page. You can also reach out to me personally on my talkpage or privately through my e-mail (soyeyele-ctr@wikimedia.org). For further general information on the universal code of conduct, please also check out our frequently asked questions page.--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 12:02, 18 Oṣù Kínní 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Fónrán Fídíò  ìpolongo fún Wikipedia èdè Yorùbá

Ẹ ku dédé ìwòyí ẹ̀yin akẹgbẹ́ mi,  Mo.ṣàkíyèsí wípé ìṣeẹ́ pọ̀ fún wa láti ṣe kí a lè jẹ́ kí àwọn ènìyàn mọ̀ nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Fúndí èyí,o fẹ́ fi àsìkò yí fi tó yín létí wípé mo ti bèrè fún ìrànwọ́ lọ́dọ àjọ WMF kí n lè ya fọ́nrán fídíò láti fi ṣe ìpolongo fún Wikipedia èdè Yorùbá. Ẹ lè wo Ìtàkùn yí fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé Ẹ seun púpọ̀. T CellsTalk 11:34, 1 Oṣù Kejì 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Wiki Loves Folklore 2021 is back!

Please help translate to your language

You are humbly invited to participate in the Wiki Loves Folklore 2021 an international photography contest organized on Wikimedia Commons to document folklore and intangible cultural heritage from different regions, including, folk creative activities and many more. It is held every year from the 1st till the 28th of February.

You can help in enriching the folklore documentation on Commons from your region by taking photos, audios, videos, and submitting them in this commons contest.

Please support us in translating the project page and a banner message to help us spread the word in your native language.

Kind regards,

Wiki loves Folklore International Team

MediaWiki message delivery (ọ̀rọ̀) 13:25, 6 Oṣù Kejì 2021 (UTC)[ìdáhùn]

community notification:Grassroot Language Documentation in Nigerian for Wikipedia and its sister projects

Hello all, We are glad to inform you of the submission of the project tagged: Grassroot Language Documentation in Nigerian for Wikipedia and its sister projects. Since this project focused on Yoruba dialects, we, therefore, welcome your feedback and comment on the project. RegradsOlaniyan Olushola (ọ̀rọ̀) 19:22, 10 Oṣù Kejì 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Proposal: Set two-letter project shortcuts as alias to project namespace globally

Please help translate to your language

Hello everyone,

I apologize for posting in English. I would like to inform everyone that I created a new global request for comment (GRFC) at Meta Wiki, which may affect your project: m:Requests for comment/Set short project namespace aliases by default globally.

In this GRFC, I propose that two-project shortcuts for project names will become a default alias for the project namespace. For instance, on all Wikipedias, WP will be an alias to the Wikipedia: namespace (and similar for other projects). Full list is available in the GRFC.

This is already the case for Wikivoyages, and many individual projects asked for this alias to be implemented. I believe this makes it easier to access the materials in the project namespace, as well as creating shortcuts like WP:NPOV, as well as helps new projects to use this feature, without having to figure out how to request site configuration changes first.

As far as I can see, Wikipedia currently does not have such an alias set. This means that such an alias will be set for you, if the GRFC is accepted by the global community.

I would like to ask all community members to participate in the request for comment at Meta-Wiki, see m:Requests for comment/Set short project namespace aliases by default globally.

Please feel free to ask me if you have any questions about this proposal.

Best regards,
--Martin Urbanec (talk) 14:13, 18 Oṣù Kejì 2021 (UTC)[ìdáhùn]


Yoruba Wikipedia Radio Program

Ẹ kú àsìkò yí gbogbo ilé,

Mo fẹ́ fi asìkò yí fi tó yín létí wípé ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians User Group ti fi ìbéèrè ìrànwọ́ láti ṣe ìpolongo orí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀-mágbèsì tí a pe akòrí rẹ̀ ní : Yoruba Wikipedia Radio Program, ránṣẹ́ sí àjọ Wikimedia fún àtìlẹyìn. Ẹ lè ka nípa ìfiṣọwọ́ yí níbí. Ẹ ṣeun.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 10:02, 28 Oṣù Kẹta 2021 (UTC)[ìdáhùn]


Ìdánilẹ́kọ́ fún àwọn tí ó wo fídíò ipolongo Wikipedia èdè Yorùbá

Ẹ kú ojúmọ́ ẹ̀yin ènìyàn mi. Mo fẹ́ fi tó yín létí wípé mo ń tọrọ fún àtìlẹyìn fún Rapid Grant. Ẹ wòó níbí

Ìpele Ìkejì Àlàkalẹ̀ Gbogboògbọ̀ fún Ìhùwàsí

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí (UCoC) yìí ṣ'ètò ìpelẹ̀sẹ̀ iwà tí ó bójú mu fún àjọṣepọ̀ Wikimedia àti àwọn iṣẹ́ àkànṣe rẹ̀ẹ̀. kárí àgbáyé. Iṣẹ́ yìí wà ni ipele ìkejì lọ́wọ́, pẹ̀lú ìjíròrò lóri bí a ṣelè gbé òfin yìí ró. O lè kà si lóri iṣẹ́ yìí nípa lílọ sí ojú-ewé rẹẹ̀.

Ìgbìmọ̀ Abánikọ:Ìpè fún ìdarapọ̀

Wikimedia Foundation ngba àwọn olùfarajìn lọ́wọ́ láti darapọ̀ mọ́ ìgbìmọ̀ tí yíò kọ bí a ṣelè gbé òfin UCoC ró. Àwọn olùfarajìn lórí ìgbìmọ̀ yìí yó jọ̀wọ́ láàrin wákàtí méjì sí mẹ́fà lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀, láti oṣù kẹ́rin títí dé oṣù kéje, àti láti oṣù kẹ́wà sí oṣù kọ́kànlá. Ó ṣe pàtàkì fún ìgbìmọ̀ yìí láti ní onírúurú ènìyàn, tí ó ní oríṣiríṣi ìrírí, yálà àwọn oníṣé tí óti pẹ́ nínú àjọṣepọ̀ yìí tàbí àwọn tí ó ṣẹ̀ darapọ̀, àti àwọn tí ó ti jẹ́ olùfaragba ìyọnu lọ́nà kan tàbí òmíràn, pẹ̀lú àwọn tí ati fi èsùn èké ìyọlẹ́nu kàn.

Láti f'orúkọ sílẹ̀ tàbí mọ̀ si nípa ètò yìí, wo Àlàkalẹ̀ Gbogboògbọ̀ fún Ìhùwàsí/Ìgbìmọ̀ Abánikọ

Ìjíròrò 2021: Àkíyèsí àti ìpè fún àwọn olùfarajìn/onítúmọ̀

Láti 5 April - 5 May 2021, àwọn ìjíròrò yí ò wáyé nínu ọ̀pọ̀ àwọn iṣẹ́ àkànṣẹ Wikimedia lórí ìgbófinró UCoC. À nwá àwọn olùfarajìn láti túnmọ̀ àwọn ohun èlò pàtàkì àti láti darí àwọn ìjíròrò ní èdè tàbí iṣẹ́ Wikimedia wọn nípa lílo àwọn ìbéèrè pàtàkì tí a dá lábàá. Tí ó bá wù ọ́ láti farajìn fún ọ̀kan lára àwọn ipọ̀ wọ̀nyí, jọ̀wọ́ késí wa nínú irú èdè tí ó bá rọrùn fún ọ.

Láti mọ̀ si nípa iṣẹ́ yìí àti àwọ̀n ìjíròrò míràn tí o nlọ lọ́wọ́, wo Àlàkalẹ̀ Gbogboògbọ̀ fún Ìhùwàsí/Àwọ̀n ìjíròrò 2021.

-- SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 20:37, 5 Oṣù Kẹrin 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Global bot policy changes

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí: Ẹṣé!

Ẹkú dé dé àsìkò yìí!

A dúpẹ́ gidigidi lọ́wọ́ gbogbo àwọn tí ó darapọ̀ mọ́ àwọn ìjíròrò lóri ìgbófìnró Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí tí a ṣe. A fẹ́ fi tó yín lé tí wípé ati parí àkótán gbogbo àwọn èsì tí a rí gbà lát'òri àwọn ìjíròrò wọ̀nyí, ẹ sì lè rí àkótán yìí kà lóri metawiki níbí. Ẹṣeun lẹ́ẹ̀kan si!--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 22:37, 14 Oṣù Kẹrin 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Ìfilọ̀ nípa ìkópa nínú ayẹyẹ Yoruba Academy Event

Ẹkú dé dé àsìkò yìí gbogbo ilé! A ń fi àsìkò yí tó yín létí wípé ilé ẹ̀kọ́ Yorùbạ́ Academy fi ìwé pè wá kí a wá sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́ àkànṣe Wikipedia ní ìlú Ìbàdàn. Inú wa dùn púpọ̀ láti fi ìròyìn ayọ̀ yí tó yín létí. Ẹ ṣeun Agbalagba (ọ̀rọ̀) 17:17, 15 Oṣù Kẹrin 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Ètò ìdìbò fun àwọn ìgbìmọ Wikimedia Foundation

Ẹ kú déédé àsìkò yí, orúkọ oníṣẹ́ mi ni User:T Cells. Mo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùrànwọ́ fún ètò ìdìbò Wikimedia Board of Trustee 2021.

Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ wípé ìdìbò sí ipò Board of Trustee ti ọdún 2021 yóò wáyé láìpẹ́, iṣẹ́ mi sì ni láti ri wípé gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians mọ̀ nípa ètò ìdìbò náà lẹ́sẹẹsẹ.

Ìgbìmọ̀ Board of Trustee ni wọ́n ń ṣe àkóso àwọn iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia pátá pátá. Àwọn tí wọ́n tí àwùjọ kọ̀ọ̀kan bá fọkàn tán tí wọ́n sì dìbò yàn ati àwọn tí àjọ fúnra wọn bá yan sípò ni wọ́n ma ń ṣiṣẹ́ pọ̀, sáà ọdún mẹ́ta ni gbogbo wọn yóò sì ló. Gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ Wikimedia pátá ni wọ́n sì ní ànfaní láti dìbò yan ẹni tí ó bá wù wọ́n.

Ẹ lè wo àwọn àlàkalẹ̀ ìgbésẹ̀ ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé níbi: https://meta.wikimedia.org/wiki/Wikimedia_Foundation_elections/2021#Timeline

Gbogbo aláfikún pátá ni wọn yóò dìbò láti yan ẹnikẹ́ni tí wọ́n fọkàn tán sí orí aga ìgbìmọ̀ mẹ́rin tí ó ṣófo ní ọdún 2021. Ànfaní rèé láti yan aṣojú wa tí ó ní ìmọ rẹ̀ gbòòrò sípò yí. Ẹ lè wo ìtàkùn yí: https://meta.wikimedia.org/wiki/Wikimedia_Foundation_elections/2021#Information_for_candidates. Láti díje sípò yí.

O lè tẹ ìtàkùn yí : https://meta.wikimedia.org/wiki/Wikimedia_Foundation_elections/2021#Voting_information láti dìbò bí o kò bá fẹ́ díje dupò kí á lè wà lára àwùjọ tí ìbò wọ pọ̀ jùlọ.

Ẹ lè fi ìbéèrè tí ẹ bá ní ṣọwọ́ sí mi. Ẹ ṣeun púpọ̀. T CellsTalk 17:58, 3 Oṣù Kẹfà 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Universal Code of Conduct News – Issue 1

Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí
Abala àkọ́kọ́, Oṣù kẹ́fà 2021Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn


A kí yin káàbọ̀ sí abala àkọ́kọ́ Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí! Ìwé ìròyìn yìí yio ran àwọn ará àjọṣepọ̀ Wikimedia lọ́wọ́ láti mọ àwọn ohun tó nṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ lórí ìlànà yìí àti bí wọ́n ṣe lè túnbọ̀ kọ́pa nínú ètò náà. A ó tún pín àwọn ìròyìn, ìwádìí, àti àwọn àpèjọ tó jọmọ́ UCoC tó nbọ̀ lọ́nà.

Ẹ jọ̀wọ́ kí è si wípé, èyí ni abala àkọ́kọ́ ìwé-ìròyìn UCoC, tí a fi ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn olùfọrúkọ sílẹ̀ àti gbogbo abẹ́-igi iṣẹ́-àkànṣe, gẹ́gẹ́ bí ìkéde fún ètò ìròyìn yìí. Tí ẹ bá fẹ́ kí a fi àwọn abala tó nbọ̀ ránṣẹ́ sí ojú-ewé ọ̀rọ̀ yin, abẹ́ igi iṣẹ́-àkànṣe yín, tàbí ojú-ewé ké'wé tó tọ̀nà, ẹ fi orúkọ yín tàbí ti ojú-ewé náà kalẹ̀ sí bí.

E lè ràn wá lọ́wọ́ láti ma túnmọ̀ àwọn abala ìwé-ìròyìn yìí sí èdè ìbílẹ̀ yín, kí a lè pólóngó ìròyìn nípa ìlànà yìí, kí a sì pèsè àbò fún gbogbo wa nínú àjọṣepọ̀ tí gbogbo wa fẹ́ràn yìí. Ẹ jọ̀wọ́ fi orúkọ yín sílẹ̀ níbí tí ẹ bá fẹ́ kí a ké sí yín fún ìtumọ̀ àwọn abala ìwé ìròyìn wa, kí a tó tẹ̀ wọ́n jádèe. Ìkópa yín ṣe pàtàkì fún wa.

  • Àwọn ìkànsí àti ìjíròrò àwọn ilé-iṣẹ́ Wikimedia – A fi ìpè ránṣẹ́ sí àwọn ilé-iṣẹ́ Wikimedia ní oríṣiríṣi ìwọ̀n àti irú àti ìrírí láti kọ́pa nínú àwọn ìjíròrò ati ìkànsí UCoC ní oṣù kẹ́ta títí dé oṣù kẹrìn 2021. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Àwọn ìkànsí àti ìjíròrò gbòógì 2021 – Wikimedia Foundation ṣ'ètò ìjíròrò àwọn ìbéèrè ìgbófìnró ní oṣù kẹ́rìn àti oṣù káàrún 2021, láti gba èsì kalẹ̀ lórí ìgbófìnró UCoC lát'ọ̀dọ̀ àwọn ará àjọṣepọ̀ Wikimedia. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Àwọn ìpàdé ìjíròrò – Àwọn olùṣètò UCoC ṣ'ètò ìpàdé ìjíròrò gbangba méjì tí ó wáyé fún ìṣẹ́jú àádọ̀rún ní oṣù káàrún 2021 láti jíròrò lórí àwọn ìbéèrè gbóògì ìgbófìnró fún UCoC. Àwọn ìpàdé míìràn sì tún nbọ̀ lọ́nà. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ìgbìmọ̀ fún kíkọ ipele ìkejì – Ìgbìmọ̀ fún kíkọ ipele ìkejì ti UCoC bẹ̀ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọjọ́ kejìlá oṣù káàrún 2021. Kà síbẹ̀ si lórí iṣẹ́ wọn.(ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Búlọ́ọ̀gì Diff – Àwọn olùṣètò UCoC kọ oríṣiríṣi búlọ́ọ̀gì lórí àwọn àkíyèsí àti èsì tí wọ́n rí gbà lát'ọ̀dọ̀ àwọn ará àjọṣepọ̀ ìbílẹ̀ tí wọ́n kàn sí ní ìbẹ̀rẹ̀ odún 2021. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)


Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí - Abala Ìkejì

Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí
Abala ìkejì, Oṣù kéèje 2021Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn


A kí yin káàbọ̀ sí abala ìkejì Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí! Ìwé ìròyìn yìí yio ran àwọn ará àjọṣepọ̀ Wikimedia lọ́wọ́ láti mọ àwọn ohun tó nṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ lórí ìlànà yìí, a ó sì tún pín àwọn ìròyìn, ìwádìí, àti àwọn àpèjọ tó jọmọ́ UCoC tó nbọ̀ lọ́nà.

Tí ẹ kò bá tí ṣ'eléyìí tẹ́lẹ̀, jọ̀wọ́ rántí láti fi orúkọ sílẹ̀ níbí tí ẹ bá fẹ́ kí a fi àwọn abala ìwé-ìròyìn tó nbọ̀ ránṣẹ́ sí yin, ẹ tún fi orúkọ yín sílẹ̀ níbí tí ẹ bá fẹ́ kí á ké sí yín fún ìtumọ̀ àwọn abala ìwé ìròyìn wa ní ọjọ́ iwájú.

  • Àtúnyẹ̀wò Ọ̀rọ̀ inú Ìlànà Ìgbófìnró - Àwọn ìpàdé ìpìlẹ̀ ìgbìmọ̀ fún kíkọ ti ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe ìsopọ̀ àwọn àkórí pàtàkì lórí ìgbófìnró, àti ṣíṣe ìfihàn àwọn ìwádìí lórí àwọn ètò tó wà nlẹ̀ àti àwọn ààfò láàrín àjọṣepọ̀ Wikimedia wa. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ìwádìí lórí Àwọn Ìfojúsìn fun Ìyọlẹ́nu - Láti ṣ'àtilẹ̀yìn fún ìgbìmọ̀ fún kíkọ, Wikimedia Foundation ṣ'ètò iṣẹ́ ìwádìí tí ó dá lórí àwọn ìrírí ìyọlẹ́nu lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ìkànsí àti Ìjíròrò fún Àwọn Alámùjútó - Láti Oṣù Kẹ́fà, Ìpàdé àwọn alámòjútó lát'òri àwọn oríṣiríṣi iṣẹ́-àkànṣe Wiki ti nwáyé, láti jíròrò lórí bí ó ti yẹ kí ọjọ́-iwájú UCoC rí ní ìrísí kárí-ayé. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Àwọn Ìpàdé fún ìjíròrò - Àwọn olùṣètò UCoC lẹ́ẹ̀kàn si, ṣètò ìpàdé fún ìjíròrò, ní àkókò yìí fún àwọn ará elédè Kòríà àti àwọn olùkópa míràn lát'orí àwọn iṣẹ́-àkànṣe ti ESEAP, láti jíròrò lórí ìgbófìnró UCoC. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ Ìsọdàṣà UCoC lát'ọ̀dọ̀ Àwọn Ará Àjọṣepọ̀ - Láti ìgbà ìfọwọ́sí Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ WMF ní oṣù kéjì 2021, àwọn ààyè tí àwọn ará àjọṣepò Wikimedia ti lo ìlànà UCoC ngbòrò si. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ago-iṣẹ́ Titun fún Ìgbìmọ̀ Adelé Ìwádìí fún Trust & Safety - Ìrètí wà tẹ́lẹ̀ fún ìparí ìgbìmọ̀ CRC ní 1 July. Ṣùgbọ́n, bí ó ti wá jẹ́ wípé ètò UCoC yí ò ṣẹlẹ̀ títí dé Oṣù Kéjìlá, ago-iṣẹ́ fún ìgbìmọ̀ CRC ti yípadà. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Wikimania - Àwọn olùṣètò UCoC ngbèrò láti wà lórí ètò Wikimania 2021, nípasè ẹ̀kọ́ ìjíròrò. Wọ́n tún gbèrò láti ní àwọn asojú ní Community Village àpèjọ náà. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Búlọ́ọ̀gì Diff - Wo àwọn àtẹ̀jádè titun lórí ètò UCoC nínú Búlọ́ọ̀gì Diff ti Wikimedia. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)

--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 16:05, 14 Oṣù Keje 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí - Àgbéyẹ̀wò àwọn ìlànà Ìgbófìnró àkọ́kọ́

Ìgbìmọ̀ fún Kíkọ ti Ipele Ìkejì Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí npè fún àwọn èrò lórí àwọn ìlànà ìgbófìnró àkọ́kọ́ ti Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí (UCoC). Àsìkò fún ìgbèròsílẹ̀ yìí ó wáyé láti 17 August 2021 títí dé 17 October 2021.

Àwọn Ìlànà kò parí síbí, ṣùgbọ́n o lè rànwá lọ́wọ́ láti gbe lọ síwájú. Ìgbìmọ̀ yìí ó ma ṣe àgbéyẹ̀wò rẹẹ̀ pẹ̀lú èrò lát'ọ̀dọ̀ àwọn ará Wikimedia.

O lè yan èdè tí ó bá wù ọ́ àti ọ̀nà tí o fẹ́ gbà kópa. A ó ṣètò àwọn ìjíròrò lórí ọ̀pọ̀ àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia, ní oríṣiríṣi èdè. A nílò àwọn olùfarajìn láti báwa ṣètò àwọn ìjíròrò lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe ti wọn.

A ti ṣ'ètò àwọn ìjíròrò ayélujára lórí ìlànà ìgbófìnró àkọ́kọ́ UCoC yìí:

Ìpàdé Wikimania 2021 - 16 August @ 11:00 UTC - 11:45 UTC
Wákàtí ìjíròrò - 24 August, 31 August, 7 September @ 03:00 UTC & 14:00 UTC
Àwọn ìpè ìjíròrò - 18 September @ 03:00 UTC & 15:00 UTC

A ó gbè àwọn àkópọ̀ ìjíròrò jáde ní ojú-ewé yìí l'ọ̀sẹ́ méjì-méjì.

Ẹ jọ̀wọ́ kàn sí mi tí ẹ bá ní ìbéèrè kankan.--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 20:40, 18 Oṣù Kẹjọ 2021 (UTC)[ìdáhùn]

2021 Board election voting opens!

Voting for the 2021 Board of Trustees election is now open. Candidates from the community were asked to submit their candidacy. After a three week long Call for Candidates, there are 19 candidates for the 2021 election.

The Wikimedia movement has the opportunity to vote for the selection of community-and-affiliate trustees. By voting, you will help to identify those people who have the qualities to best serve the needs of the movement for the next several years. The Board is expected to select the four most voted candidates to serve as trustees. Voting closes 31 August 2021.

The Wikimedia Foundation Board of Trustees oversees the Wikimedia Foundation's operations. The Board wants to improve their competences and diversity as a team. They have shared the areas of expertise that they are currently missing and hope to cover with new trustees.

Learn more about candidates. Learn about the Board of Trustees. Vote.

Read the full announcement.

Best, The Elections Committee

--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 23:23, 18 Oṣù Kẹjọ 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí - Abala Ìkẹ́tàa

Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí
Abala ìkẹ́tàa, Oṣù kẹ́jọ̀ọ 2021Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn


A kí yin káàbọ̀ sí abala ìkẹ́tàa Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí! Ìwé ìròyìn yìí yio ran àwọn ará àjọṣepọ̀ Wikimedia lọ́wọ́ láti mọ àwọn ohun tó nṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ lórí ìlànà yìí, a ó sì tún pín àwọn ìròyìn, ìwádìí, àti àwọn àpèjọ tó jọmọ́ UCoC tó nbọ̀ lọ́nà.

Tí ẹ kò bá tí ṣ'eléyìí tẹ́lẹ̀, jọ̀wọ́ rántí láti fi orúkọ sílẹ̀ níbí tí ẹ bá fẹ́ kí a fi àwọn abala ìwé-ìròyìn tó nbọ̀ ránṣẹ́ sí yin, ẹ tún fi orúkọ yín sílẹ̀ níbí tí ẹ bá fẹ́ kí á ké sí yín fún ìtumọ̀ àwọn abala ìwé ìròyìn wa ní ọjọ́ iwájú.

  • Àwọn Ìlànà Ìgbófìnró Àkọ́kọ́ - A ti ṣe àtẹ̀jáde Àwọn Ìlànà Ìgbófìnró Àkọ́kọ́ fún Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí lórí meta ní oríṣiríṣi èdè. Àwọn ìlànà yìí ní àwọn ìtumọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ titun, ó sì pèsè ìmọ̀ràn lórí àwọn ètò ìgbófìnró ìbílẹ̀. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Àtúnyẹ̀wò Ọ̀rọ̀ inú Ìlànà Ìgbófìnró - Kí a tó parí àwọn ìlànà ìgbófìnró, àgbéyẹ̀wò àti ìjíròrò gbọdọ̀ wáyé pẹ̀lú àwọn ará Wikimedia. Àwọn olùṣètò ti ṣètò àwọn wákàtí àti ìpè ìjíròrò lákòkó àgbéyẹ̀wò yìí. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Àwọn Wákàtí àti Ìpè Ìjíròrò - Láti gbọ́ èrò àwọn ará àjọṣepọ̀ lórí àwọn ìlànà ìgbófìnró àkọ́kọ́ ti àwọn ìgbìmọ̀ fún kíkọ ti gbékalẹ̀, Àwọn olùṣètò UCoC yí ó ṣ'ètò wákàtí ìjíròrò ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ìpalẹ̀mọ́ Wikimania - Àwọn olùṣètò ṣètò Ìjókò ìjíròrò ní Wikimania 2021, tí ó ní àwọn ará ìgbìmọ̀ onígbọ̀wọ́ àti òṣìṣẹ́ WMF. Ìjókò yìí pèsè àwọn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ lórí bí a ṣe kọ Àwọn Ìlànà Ìgbófìnró Àkọ́kọ́ yìí, àti àwọn ìgbésẹ̀ tí à ngbèrò. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ìtúmọ̀ - Bí ó ti jẹ́ wípé ọ̀pọ̀ lára àwọn ará Wikimedia ni kọ̀ gbọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì, síbẹ̀ UCoC tabá gbogbo ará, iṣẹ́-àkànṣe káàkiri Àjọṣepọ̀ Wikimedia, ó jẹ́ ohun pàtàkì láti pèsè àtìlẹ́yìn tó péye fún àwọn èdè lákòkò ètò yìí. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Búlọ́ọ̀gì Diff - Wo àwọn àtẹ̀jádè titun lórí ètò UCoC nínú Búlọ́ọ̀gì Diff ti Wikimedia. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ètò Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ WMF 2021 - Jọ̀wọ́ ka àgbékalẹ̀ àwọn olùdíje kí o sì dìbò!(ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)

--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 16:57, 27 Oṣù Kẹjọ 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Èsì fún ètò ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation tí ó gbajúmọ̀ jùlọ

Adúpẹ́ lọ́wọ́ gbogbo ènìyàn tó kópa nínú ètò ìdìbò 2021. Ìgbìmọ̀ elétò ìdìbò ti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ìbò fún Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2021, tí wọ́n ṣ'ètò láti yan àwọn alága mẹ́rin titun. Àwọn ènìyàn 6,873 káàkiri àwọn iṣẹ́-àkànṣe 214 ni ó fi ìbò sílẹ̀. Àwọn olùdíje mẹ́rìn yìí ni ó borí:

  1. Rosie Stephenson-Goodknight
  2. Victoria Doronina
  3. Dariusz Jemielniak
  4. Lorenzo Losa

Nígbàtí ati yan àwọn olùdíje nípasẹ̀ ìdìbò ará àjọṣepọ̀, Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ kò tí yàn wọ́n. Wọ́n síbẹ̀ ní láti yege àwọn ìwádìí abẹ́lẹ̀ nípa wọn àti yege nínú àwọn òfin tí ó yẹ. Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti gbà láti yan àwọn alága titun ní ìparí oṣù yìí.

Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìkéde níbí.--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 22:48, 7 Oṣù Kẹ̀sán 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Movement Charter Drafting Committee - Community Elections to take place October 11 - 24

This is a short message with an update from the Movement Charter process. The call for candidates for the Drafting Committee closed September 14, and we got a diverse range of candidates. The committee will consist of 15 members, and those will be (s)elected via three different ways.

The 15 member committee will be selected with a 3-step process:

  • Election process for project communities to elect 7 members of the committee.
  • Selection process for affiliates to select 6 members of the committee.
  • Wikimedia Foundation process to appoint 2 members of the committee.

The community elections will take place between October 11 and October 24. The other process will take place in parallel, so that all processes will be concluded by November 1.

For the full context of the Movement Charter, its role, as well the process for its creation, please have a look at Meta. You can also contact us at any time on Telegram or via email (wikimedia2030@wikimedia.org).--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 19:46, 23 Oṣù Kẹ̀sán 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Ifilo

Ẹ kú dédé àsìkò yí oo. A ní kí a fi tó yín létí wípé a ó ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa bí a ṣe lè ṣe àfikún sí Wikidata ní èdè Yorùbá. Ẹ ṣeun púpọ̀. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 12:56, 25 Oṣù Kẹ̀sán 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Ìfitónilétí

Ẹ kú àsìkò yí, a ní kí afi tó yín létí wípé a fẹ́ ṣe idije fun AfroCine ni inú oṣù tí ó ń bọ̀. Ẹ kú ojú lọ́nà.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 15:06, 6 Oṣù Kẹ̀wá 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Universal Code of Conduct Draft Enforcement Guidelines review still needs your ideas and opinions

Hello, this is just a reminder that the Universal Code of Conduct Draft Enforcement Guidelines are open for review and comment. The Drafting Committee will start working on revisions and improvement in less than two weeks (October 17), so it is important that you give them your ideas and opinions soon!

There is now a short, simple version of the Draft Guidelines here to make your review easier. If possible, also help translate the short version into more languages!

We will also hold one last conversation hour on October 15, 2021 03:00 and 14:00 UTC.

On behalf of the Drafting Committee, much thanks to everyone who has given ideas so far. We hope to hear from more of you - the Guidelines will be much stronger if more opinions are included.--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 16:12, 6 Oṣù Kẹ̀wá 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Movement Charter Drafting Committee (MCDC) Election Starts

Voting for the election for the members for the Movement Charter drafting committee is now open. In total, 70 Wikimedians from around the world are running for 7 seats in these elections.

Voting is open from October 12 to October 24, 2021.

The committee will consist of 15 members in total: The online communities vote for 7 members, 6 members will be selected by the Wikimedia affiliates through a parallel process, and 2 members will be appointed by the Wikimedia Foundation. The plan is to assemble the committee by November 1, 2021.

  • We are piloting a voting advice application for this election. Click yourself through the tool and you will see which candidate is closest to you!

--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 16:27, 13 Oṣù Kẹ̀wá 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí - Abala Ìkẹ́rìn

Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí
Abala ìkẹ́rìn, Oṣù kẹ́jọ̀ọ 2021Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn


A kí yin káàbọ̀ sí abala ìkẹ́rìn Ìròyìn Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí! Ìwé ìròyìn yìí yio ran àwọn ará àjọṣepọ̀ Wikimedia lọ́wọ́ láti mọ àwọn ohun tó nṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ lórí ìlànà yìí, a ó sì tún pín àwọn ìròyìn, ìwádìí, àti àwọn àpèjọ tó jọmọ́ UCoC tó nbọ̀ lọ́nà.

Jọ̀wọ́ rántí láti fi orúkọ sílẹ̀ níbí tí ẹ bá fẹ́ kí a fi àwọn abala ìwé-ìròyìn tó nbọ̀ ránṣẹ́ sí yin, ẹ tún fi orúkọ yín sílẹ̀ níbí tí ẹ bá fẹ́ kí á ké sí yín fún ìtumọ̀ àwọn abala ìwé ìròyìn wa ní ọjọ́ iwájú.

  • Ìkánlẹ̀ Àgbéyẹ̀wò Ọ̀rọ̀ inú Ìlànà Ìgbófìnró Àkọ́kọ́ - Àgbéyẹ̀wò àwọn ìlànà Ìgbófìnró àkọ́kọ́ ti Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí yí ò wá sí òpin ní 17 October 2021, lẹ́yìn ìkànsí oṣù méjì. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Àwọn Wákàtí àti Ìpè Ìjíròrò - Àsìkò ìjókò míìràn láti jíròrò lórí EDGR wáyé ní àṣèyọrí ní 18 September 2021. Wákàtí ìjíròrò kan tí yí ò gbẹ̀yìn yí ò wáyé ní 15 October 2021.(ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ètò ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ kíkọ ti Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀ - Ètò ìdìbò Ìgbìmọ̀ Kíkọ ti Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀ ti bẹ̀rẹ̀, yí ò sì wá sí òpin ní 25 October 2021. Àwọn oníṣẹ́ iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia lè dìbò fún àwọn olùdíje tí wọ́n fẹ́ràn jùlọ ṣ'órí ìgbìmọ̀ náà. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Ìdarí Titun fún Ìwé-Ìròyìn yìí - Bí a ṣé nkágbá ètò ìkànsí fún Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí, ẹgbẹ́ olùṣètò ngbèrò ìdarí titun fún ìwé-ìròyìn yìí. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)
  • Búlọ́ọ̀gì Diff - Wo àwọn àtẹ̀jádè titun lórí ètò UCoC nínú Búlọ́ọ̀gì Diff ti Wikimedia. (ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́)

--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 21:50, 14 Oṣù Kẹ̀wá 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Learn how Movement Strategy Implementation Grants can support your Movement Strategy plans

Please be informed that the Movement Strategy Implementation grants is back and it now provides more than $2,000 USD to put Movement Strategy plans into action. Find out more about Movement Strategy Implementation grants, the criteria, and how to apply here

Also, the Movement Charter Drafting Committee election is still ongoing. It would be great to increase community participation. If you haven't voted, now is the time. Please vote here before October 24.

Thank you!--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 16:28, 20 Oṣù Kẹ̀wá 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Meet the new Movement Charter Drafting Committee members

The Movement Charter Drafting Committee election and selection processes are complete.

The committee will convene soon to start its work. The committee can appoint up to three more members to bridge diversity and expertise gaps.

If you are interested in engaging with Movement Charter drafting process, follow the updates on Meta and join the Telegram group.

With thanks from the Movement Strategy and Governance team.--SOyeyele (WMF) (ọ̀rọ̀) 17:52, 1 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Congratulations to the elected and selected members of the drafting committee, they are all welcome on board. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 10:59, 3 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)[ìdáhùn]

Ìjábọ̀ Ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians User Group fún ọdún 2021-2022

Ẹgbẹ́ Yorùbá Wikimedians User Group ń fi akókò yí kéde rẹ̀ fún gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ ati àwọn aláfikún sí ọpọ́n ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Yorùbá Wikipedia wípé èsì tabí àbọ̀ àwọn iṣẹ́ àkànṣe ọlọ́kan-ò-jọ̀kan tí a ti gbé ṣe láàrín ọdún 2021 ti wà ní akọsílẹ̀ báyí fún àgbéyẹwò yín, kí ẹ sì lè mọ bí ẹgbẹ́ náà ti ń sapá láti mú ìdàgbà-sókè bá ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia èdè Yorùbá àti gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ aláfikún Yorùbá Wikipedia lápapọ̀ ṣe ń kópa ribi ribi sí. Ẹ lè ìtàkùn ìsàlẹ̀ yí láti kà nípa rẹ̀. https://meta.wikimedia.org/wiki/Yoruba_Wikimedians_User_Group/2021_Report Ẹ ṣeun Agbalagba (ọ̀rọ̀) 18:06, 7 Oṣù Kọkànlá 2021 (UTC)[ìdáhùn]