Qaribullah Nasiru Kabara
Ìrísí
Sheikh Qaribullah Nasir Kabara Al-Malikiy, tí wọ́n tún mọ̀ sí Al-Ash’ariy, Al-Qadiriy (tí wọ́n bí ní 17 February 1959) jẹ́ olùdarí ẹgbẹ́ Qadriyyah Sufi ní Nàìjíríà, àti ní agbègbè ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀. Ó di Khalifa ní ọdún 1996 lẹ́yìn ikú bàbá rẹ̀, ìyẹn Sheikh Muhammad Nasir Kabara.[1][2][3][4]
Òun ni àbúrò Abduljabbar Nasiru Kabara.[5]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Qaribullah sí ìlú Kano, ní Nàìjíríà, ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 1959. Ìyá rẹ̀ kú lẹ́yìn tí wọ́n bi sáyé.[1][3]
Ó gba oyè B.A. nínú ẹ̀kọ́ èdè Arabic láti ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti Bayero University ní ọdún 1994.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "'Ina da ajiyayyen silin gashin Manzon Allah'". BBC News Hausa (in Èdè Hausa). 2020-12-11. Retrieved 2023-01-18.
- ↑ Saddiq, Mustapha (2017-05-09). "Sheikh Qaribullah na nan lafiya tare da iyalan sa". Legit.ng – Nigeria news (in Èdè Hausa). Retrieved 2021-08-07.
- ↑ 3.0 3.1 "Qaribullah Nasir-Kabara Archives". The Eagle Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-07.
- ↑ saynigeria (2018-01-03). "President Buhari Receives Delegation of Qadiriyya Movement In Africa". SayNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-07.
- ↑ Aminu, Habibu Umar (2021-02-04). "The man Sheikh Abduljabbar Kabara - who's he?". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-18.