Rafael Correa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Rafael Correa
Correarafael15012007-4.jpg
Aare ile Ekuador
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
January 15, 2007
Vice President Lenín Moreno
Asíwájú Alfredo Palacio
Arọ́pò Lenín Moreno
President pro tempore of the Union of South American Nations
Lórí àga
August 10, 2009 – November 26, 2010
Asíwájú Michelle Bachelet
Arọ́pò Bharrat Jagdeo
Alakoso Okowo ati Inawo ile Ekuador
Lórí àga
April 20, 2005 – August 8, 2005
Asíwájú Mauricio Yepez
Arọ́pò Magdalena Barreiro
Leader of PAIS Alliance
Lọ́wọ́
Ó bọ́ sí orí àga
April 3, 2006
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Oṣù Kẹrin 6, 1963 (1963-04-06) (ọmọ ọdún 54)
Guayaquil, Ecuador
Ẹgbẹ́ olóṣèlú PAIS Alliance
Tọkọtaya pẹ̀lú Anne Malherbe
Alma mater University of Illinois at Urbana-Champaign
Université catholique de Louvain
Universidad Católica de Santiago de Guayaquil
Ẹ̀sìn Roman Catholicism
Ìtọwọ́bọ̀wé

Rafael Vicente Correa Delgado (Pípè: [rafaˈel βiˈsente koˈre.a ðelˈɣaðo]; ojoibi April 6, 1963)[1] ni Aare Orile-ede Olominira ile Ekuador lati 2007 ati lowolowo Aare pro tempore Isokan awon Omoorile-ede Guusu Amerika. Onimo oro-okowo to keko ni Ecuador, Belgium ati US, o je fun igba soki bi Alakoso Inawo orile-ede re ni 2005. O je didiboyan bi Aare ni opin 2006 o si gun ori aga ni Osu Kinni 2007.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]