Jump to content

Rama Brew

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rama Brew
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Iṣẹ́Actress, television personality and jazz musician
Ìgbà iṣẹ́1972–present
Gbajúmọ̀ fúnAvenue A, Villa Kakalika, Farewell to Dope, Ultimate Paradise
Àwọn ọmọMichelle Attoh
Parent(s)Michelle Attoh

Rama Brew jẹ́ òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ Ghana àti olóòtú ètò lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ olórin.[1][2][3]

Ìtàn lórí ìbẹẹrẹ ayé Rama Brew

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Rama ti ni lọ́kàn láti di oníjó láti ìgbà èwe rẹ̀, àmọ́ bàbá rẹ̀ kò gbà. Lẹ́yìn náà ni àbúrò bàbá rẹ̀ tó ń ṣiṣẹ́ ní Ghana Broadcasting Corporation(GBC) mú wọ iṣẹ́ lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán.[4]


Siwaju si

Rama ni omobirin kan ti oruko re n je Michelle Attoh ti oun naa si je oserebirin.

  1. Ofori, Oral. "Rama Brew Tells Youth To Be Wary Of Showbiz, Also Asks Actors' Guild To Protect Artistes". Modern Ghana. Retrieved 31 August 2017. 
  2. Yaob. "Mother of Ghollywood- Rama Brew". ModernGhana. Retrieved 4 September 2017. 
  3. "How hockey curtailed Rama Brew's sporting career". GhanaWeb. Retrieved 4 September 2017. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. Ofori, Oral. "Rama Brew Tells Youth To Be Wary Of Showbiz, Also Asks Actors' Guild To Protect Artistes". ModernGhana. Retrieved 4 September 2017. 

Àdàkọ:Authority control

Àdàkọ:Ghana-actor-stub