Robert Curl

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Robert Curl (2009)

Robert Curl je onimo sayensi to gba Ebun Nobel ninu Kemistri.

Robert Floyd Curl Jr. (ọmọ bíbí ọjọ ketalelogun oṣù Kẹjọ, ọdún 1933) ọmọ ifásitì American Professor Emeritus, Pitzer–Schlumberger olukọni ìmọ sáyẹnsì Emeritus, ati olukọni ìmọ kemistri Emeritus ni Rice University.[1] o gba àmì ẹ̀yẹ Nobel Prize in Chemistry ni ọdún 1996 fún iṣẹ iwadi nanomaterial buckminsterfullerene, ohùn pẹlu Richard Smalley (also of Rice University) àti Harold Kroto ọmọ ilẹ̀ ìwé University of Sussex.




Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Robert F. Curl". Department of Chemistry, Rice University. Archived from the original on 21 June 2016. Retrieved 19 July 2016.