Irène Joliot-Curie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Irène Joliot-Curie

Ìbí 12 Oṣù Kẹ̀sán, 1897(1897-09-12)
Paris, France
Aláìsí 17 Oṣù Kẹta, 1956 (ọmọ ọdún 58)
Paris, France
Ọmọ orílẹ̀-èdè French
Pápá Chemistry
Ibi ẹ̀kọ́ Sorbonne
Doctoral advisor Paul Langevin
Ó gbajúmọ̀ fún Transmutation of elements
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí Nobel Prize for Chemistry (1935)

Irène Joliot-Curie (12 September 1897 – 17 March 1956) je onimo sayensi ara Fransi, ohun ni omobinrin Marie Skłodowska-Curie ati Pierre Curie ati iyawo Frédéric Joliot-Curie. Lokanna mo oko re, Joliot-Curie gba Ebun Nobel fun Kemistri ni 1935 fun iwari won iranna afowose. Eyi so ebi Curie di ebi to ni awon elebun Nobel julo titi doni.[1] Bakanna awon omo mejeji awon Joliot-Curies, Hélène ati Pierre na je onimo sayensi pataki.[2]

Irène Curie + Frédéric Joliot (1934)


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nobel Laureates Facts: 'Family Nobel Laureates'". Nobel Foundation. 2008. http://nobelprize.org/nobel_prizes/nobelprize_facts.html. Retrieved 2008-09-04. 
  2. Byers, Nina; Williams, Gary A. (2006). "Hélène Langevin-Joliot and Pierre Radvanyi". Out of the Shadows: Contributions of Twentieth-Century Women to Physics. Cambridge, UK: Cambridge University Press. ISBN 0521821975.