Pierre Curie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pierre Curie
Pierre Curie
Ìbí15 May 1859
Paris, France
Aláìsí19 April 1906(1906-04-19) (ọmọ ọdún 46)
Paris, France
Ọmọ orílẹ̀-èdèFrench
PápáPhysics
Ibi ẹ̀kọ́Sorbonne
Doctoral studentsPaul Langevin
André-Louis Debierne
Marguerite Catherine Perey
Ó gbajúmọ̀ fúnRadioactivity
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1903)
Notes
Married to Marie Curie (m. 1895), their children include Irène Joliot-Curie and Ève Curie.

Pierre Curie (15 May 1859 – 19 April 1906) je omo orile-ede Fransi to je onimo fisiyiki, asiwaju ninu kristalografi, isegberingberin, piezoelectricity ati radiolilagabra, ati elebun Nobel. Ni 1903 o gba Ebun Nobel ninu Fisiyiki pelu iyawo re, Maria Skłodowska-Curie, ati Henri Becquerel, "fun idamo ise pataki ti won se nipa iwadi papo won lori isele itankakiri ti Ojogbon Henri Becquerel se awari."



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]