Roger Hallam (Ajàjàgbara)
Julian Roger Hallam [1] (tí a bí ní ọdún 1965/1966 ) [2] jẹ́ ajàfitafita àyíká tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ Extinction Rebellion , [3] [4] Just Stop Oil, [5] Insulate Britain, [6] àjọ ẹgbẹ́ Àjùmọ̀se Radical. Routes , [7] ati ẹgbẹ́ òṣèlú Burning Pink . [8] Ní Oṣù Kẹrin ọdún 2024, Hallam gba ìdá dúró fún ọdún méjì fún ìgbìyànjú láti dènà pápá ọkọ̀ òfurufú Heathrow pẹ̀lú dírọ́ọ̀nù. Ní Oṣù Keje ọdún 2024, Hallam jẹ̀bi ẹ̀sùn ti rìkísí láti dá ìrúkèrúdò àwùjọ sílẹ̀ fún sí ṣètò ìfẹ̀hónúhàn láti dínà opopona M25 ní ọdún méjì sẹ́yìn, fún èyí tí ó lọ sí ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún.[2]
Ìtàn Ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdílé Methodist ni ó tọ́ Hallam dàgbà .
Ní ọdún 1987, ó gbé ní òpópónà Gúsù ní Hockley, ó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ òṣìṣẹ́ ìwọ̀fún. Ó farahàn nínú onídàájọ́ Bow Street fún yíya àwòrán àwọn ìfiránsẹ́ àlàáfíà ìpakòkòrò-ìparun lórí ilẹ̀ Ilé -iṣẹ́ ti Ìdáábòbò ní ti Ash Wednesday ní ọdún 1987.Ní ọdún 1988,ó di fífarahàn ní ilé-ẹjọ́ Birmingham Crown fún kíkọ àtẹ̀jísẹ́ obìnrin lórí àtẹ ìpolongo ìfarahàn ọkọ̀. Èyí mú inú bí àwọn obìnrin ní oṣù keje ọdún 1987 lórí ìpolongo Austin Maestro ní Hockley Circus.
Ní ọdún 1990, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùfọwọ́sowọ́pò tí ó sì ṣí ilé ìtajà ajewé ní Saltley. [9] Láti oṣù karùn-ún ọdún 1993, o jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìfọwọ́sowọ́pọ̀ oúnjẹ ní òpópónà Gúsù ní Hockley, lẹ́yìn gbígbé ní West Virginia. [10] Ó ń gbé ní ilé irú agbègbè kan, pẹ̀lú ènìyàn mẹfa, pẹ̀lú pípín iṣẹ́. [11]
Ó jẹ́ àgbẹ̀ àtọwọ́dá tẹ́lẹ̀ lórí ilẹ̀ 10 acres (4 ha) kékeré nítòsí Llandeilo ní South Wales ; ó ṣe ìkápá ìparun ti òwò rẹ̀ sí lẹ́sẹẹsẹ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ọjọ́ tí ó burú jọjọ .
Ó kéré tán ọdún 2017 àti ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ọdún 2019, ó ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kẹta ní King's College London,[12] Ṣíṣe ìwádìí ve social change through civil disobedience and radical movements.[13]lórí bí a ṣe lè ní ìyípadà àwùjọ nípasẹ̀ àìgbọràn àti ìgbésẹ̀ ìpìlẹ̀.
Iṣẹ́ òsèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ìparí ọdún 2017, Hallam jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ asíwájú ti ẹgbẹ́ ajàjàgbara Dáwọ́ pípa àwọn ará ìlú London, [14] ìpolongo títako-ìdọ̀tí [15] ti àìgbọràn abẹ́lé tí wọ́n nírètí pé yóò já sí ìmúni àti ati ìtìmọ́lé ti àwọn ajàjàgbara. [16] Hallam pẹ̀lú Stuart Basden, Ian Bray àti Genny Scherer ni wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àti pé díẹ̀ nínú wọn ṣe àdéhùn láti lọ sí ìdasẹ́sílẹ̀ ebi ti wọ́n bá di fífi sí ìtìmọ́lé. [17]
Hallam jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ti ẹgbẹ́ irọ̀sírọ̀ àyíká Ìparun Ìsọ̀tẹ̀ , pẹ̀lú Gail Bradbrook àti Simon Bramwell. [3] [13] [18] Kò ṣe àṣeyọrí nínú Ìdìbò Ilé-ìgbìmọ̀ Yúróòpù ní ọdún 2019 ní agbègbè Lọ́ńdọ́ọ̀nù gẹ́gẹ́ bí òmìnira, tí ó borí 924 nínú ìbò 2,241,681 tí wọ́n dì(0.04%). [19]
Ní Oṣù Kẹsàn-án ọdún 2023, Hallam wà ní ipò kẹrìnlélọ́gbọ̀n lórí Àkójọ Agbára Òsì ti Orílẹ̀-èdè Tuntun ti àwọn èèkàn apá òsì tí ó ní ipa ní UK.
Ìwòye lórí ìpanirun àti àwọn ẹ̀sẹ̀ ìbálòpọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pẹ̀lú Die Zeit ní ogúnjọ́ oṣù kọkànlá ọdún 2019, Hallam sọ pé ìpanirun dà gẹ́gẹ́ bí “bí ìṣẹ̀lẹ̀ déédé” nínú ìtàn àti pé ó tún pe Holocaust náà “ó kàn jẹ́ rádaràda mìíràn nínú ìtàn ènìyàn”. [20] [21] Ó sọ ọ̀rọ̀ yìí ní ààyè tí ìjíròrò ti gbòòrò nípa ìpanirun ní èyí tó ti ṣẹlẹ̀ kárí ìtàn ọmọnìyàn, ní èyí tí Hallam fi wé ti Nazi Holocaust sí ti ìwà ìbàjẹ́ ní Congo Free State ní sẹ́ńtúrì ọ́kàndínlógún sẹ́yìn, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe sọ, òtítọ́ ọ̀rọ̀ ibẹ̀ ni pé, ọ̀gọ̀rọ̀ ènìyàn ni ó ti di pípa ní ọ̀nà tí kò tọ́ ní ojoojúmọ́ láti ìparun Ìsọ̀tẹ̀ ní ọdún 2020. árí ìtàn" ó sì tún sọ pé àwọn ará Belgian lọ sí Congo ní sẹ́ńtúrì ọ́kàndínlógún wọ́n sì pa ènìyàn ìdá mẹ́wàá. Ìfiwéra àríyànjiyàn Hallam rí àtìlẹyìn láti ọ̀dọ̀ àwọn ajàjàgbara ilẹ̀ Áfíríkà ìdádúró Maangamizi: A dènà ìpanirun / ìparun pátápátá! Ìpolongo, tí wọ́n ṣe pàtàkì ohùn rẹ̀, ṣùgbọ́n tí ó yìn ín fún òtítọ́ rẹ̀ àti ìfarajìn rẹ̀ láti sàfihàn àwọn ẹ̀sùn tí agbára ìmúnisìn ti hù ní ilẹ̀ Áfíríkà. Bákan náà, àwílé rẹ̀ nípa ìparun náà, tí àwọn olulùtakò- ẹ̀sìn gbọ́, èyí tí ó yọrí sí lílé rẹ̀ láti Ìparun Ìsọ̀tẹ̀ ní ọdún 2020.
Nínú ìwé pélébé ti ara ẹni tí ó kọ nínú túbú ní ọdún 2019, Hallam kọ̀wé pé aáwọ̀ ojú - ọjọ́ yóò já sí ìfipábánilòpọ̀ púpọ̀, àti pé ó ṣe àfihàn ìtàn kan nínú èyí tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ obìnrin ti òǹkàwé náà jẹ́ fí ipá bá lòpọ̀ láti ọwọ́ ọ̀pọ̀ èèyàn àti pé òǹkàwé náà di fífi agbára mú láti wò ó. Ìwé pélébé náà di bíbu ẹnu àtẹ́ lù láti ọwọ́ Farah Nazeer, Alákòóso ti Ìrànlọ́wọ́ fún àwọn Obìnrin . [22] Nígbà tí Der Spiegel fún Hallam lésì pe "O kò lè dá ìyípadà ojú-ọjọ́ lẹ́bi fún ìfipánilòpọ̀ ti àwọn obìnrin nígbà ogun", ìdáhùn Hallam ni "Bẹ́ẹ̀ kọ́, ìyípadà ojú-ọjọ́ jẹ́ òpó tí gáàsì ti sọ̀kalẹ̀ ní iyẹ̀wù gáàsì. Ó kàn jẹ́ ìlànà nípasẹ̀ èyí tí ìran kan tí ń pa ìran tí ó ń bọ̀”. [23]
Àwọn ẹ̀sùn ìbàjẹ́ ọ̀daràn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní osù kìíní ọdún 2017, nínú ìgbésẹ̀ láti rọ King's College London láti kúrò níbi epo fósìlì , Hallam àti ẹlòmíràn, David Durant, lilo omi-tí-ó-túká ìyẹ̀fun-orísun ọ̀dà kíkùn, ya "kúrò níbi epo àti gáàsì", "Báyìí !" àti "àìsí àkókò" lórí ẹnu-ọ̀nà ilé-ẹ̀kọ́ gíga Strand. [24] [12] tí wọ́n sì san owó ìtanràn £500 . Ní oṣù kejì tí wọ́n tún kun Great Hall ilé-ẹ̀kọ́ gíga náà eléyìí tí ó fa nǹkan tó bàjẹ́ tó tó £7000 tí wọ́n sì mú wọn . [24]
Ní Oṣù Karùn-ún ọdún 2019, lẹ́hìn ìgbẹ́jọ́ ọjọ́ mẹ́ta ní Ilé-ẹjọ́ Crown Southwark fún ìbàjẹ́ ọ̀daràn, ìgbìmọ̀ kan ti yọ wọ́n kúrò ní gbogbo àwọn ẹ̀sùn, lẹ́yìn jíjiyàn ní ìsègbè wọn pé ìṣe wọn jẹ́ ìdáhùn tí ó yẹ sí aáwọ̀ ojú-ọjọ́, pẹ̀lú Hallam jiyàn awọn ìgbésẹ̀ rẹ̀ jẹ́ òfin lábẹ́ ìdásílẹ̀ ní Òfin Bíbàjẹ́ Ọ̀daràn tí ó fún un láàyè ìbàjẹ́ tí ó bá dáàbò bò ohun-ìní mìíràn. [12] [25] Ní Oṣù Kẹta ọdún 2017, Hallam lọ sí ìdasẹ́sílẹ̀ ebi láti bèèrè fún yíyọ kúrò ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga àwọn epo fósìlì — ilé-ẹ̀kọ́ náà ní mílíọ̀nù pọ́nùn tí a ṣe ìdókòwó ni àwọn epo fósìlì ṣùgbọ́n kò sí ìdókòwó ní agbára ìsọdọ̀tun . Ọ̀sẹ̀ márùn-ún lẹ́hìn ìfẹ̀hónúhàn àkọ́kọ́, ilé-ẹ̀kọ́ gíga yọ mílíọ̀nù £14 kúrò tí àwọn ìdókòwó láti àwọn ilé-iṣẹ́ ìdáná fósìlì àti ṣe àdéhùn láti di dídojú èròǹgbà ní ọdún 2025. [26]
Ìgbìyànjú títi pápákọ̀ òfurufú Heathrow
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Hallam àti àwọn ajàjàgbara mẹ́rin mìíràn ni ó di mímú lórí ìfurasí ti rìkísí láti dá wàhálà sílẹ̀ ní ìgboro ní ọjọ́ kejìlá oṣù Kẹsano ọdún 2019, ṣáájú ọjọ́ ìṣe tí a gbèrò si àwọn awakọ̀ ní agbègbè ìyàsọ́tò ní àyíká Pápá ọkọ̀ òfurufú Heathrow láti lè dá àwọn ọkọ̀ òfurufú dúró. [27] Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta, nínú ìṣe tí Heathrow Pause se ètò rẹ̀, Hallam di mímú ní agbègbè ti Pápá ọkọ̀ òfurufú Heathrow tí ó hàn gbangba ni ìrúfin àwọn ipò gbígbanisílẹ̀ láti ìmúni ìṣáájú tí ó nílò kí ó má sí láàárín ibùsọ̀ márùn-ún(kìlómítà mẹ́jọ) 5 miles (8 km)ti pápá ọkọ̀ òfurufú èyíkéyìí tàbí gba irinsẹ́ ìyàwòrán orí òfurufú. ohun èlò. [28] Wọ́n fi í sí àtìmọ́lé títí di ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹwàá. [29]
Ní Ọjọ́ karùn-ún Oṣù Kẹrin Ọdún 2024, Hallam di rírán lọ sí ẹ̀wọ̀n ọdún méjì tí ó di dídádúró fún oṣù méjìdínlógún fún gbígbé sùnmọ̀mí láti ti pápá ọkọ̀ òfurufú Heathrow ní lílo àwọn ohun èlò ayàwòrán òfurufú bí ọ̀nà ìsàfihàn àtakò sí ṣíṣí ojú òpópónà kẹta ní pápá ọkọ̀ òfurufú náà. Hallam ati àwọn olùfisùn rẹ̀ tí sọ pé ìṣe náà jẹ́ “ìdárayá ìkéde nìkan”. Síbẹ̀síbẹ̀, Ìsègbè yìí di kíkọ̀ láti ọwọ́ àwọn olùgbẹ́jọ́.[30]
Ìdènà M25
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù Keje ọdún 2024, Hallam àti àwọn mẹ́rin mìíràn ni wọ́n jẹ̀bi pé wọ́n gbìmọ láti dínà lílọ bíbọ̀ lórí òpópónà M25, òpópónà tó yípo ojúlówó Lọ́ńdọ́ọ̀nù. Wọ́n ti mú Hallam nínú ìkọlù òwúrọ̀ ní ilé rẹ̀ ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Kẹwàá Ọdún 2023. [5] Èrò Hallam tí ó di gbígbé jáde ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́ ìdíwọ́ lórí òpópónà. [31] Ìgbẹ́jọ́ tí àwọn adájọ́ náà wáyé ní Ìlú Lọ́ńdọ́ọ̀nù àti pé ó jẹ́ àmì nípasẹ̀ àwọn ìjáde léraléra láti ọ̀dọ̀ àwọn afẹ̀sùnkàn lẹ́hìn ìdájọ́ kan láti ọ̀dọ̀ Adájọ́ Christopher Hehir tí ó kọ̀ fún wọn láti lo ìdínkù ojú-ọjọ́ bí ààbò fún àwọn ìṣe wọn. [32] Ní àkókò kan, Hallam kọ̀ láti kúrò nínú àpótí ìjẹ́rìí àti pé a mú un ní òtítọ́ fún ẹ̀gàn tí wọ́n sì rán an ní túbú. Kódà , ẹ̀ẹ̀meje ni ọlọ́pàá di pípè sí ilé-ẹjọ́ tí ó sì ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìmúni. Adájọ́ ilé-ẹjọ́ fihàn pé Hallam àti àwọn olùjẹ́jọ́ rẹ̀ yòókù yóò kojú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ní ẹ̀wọ̀n . [33]
Àwọn adájọ́ rí i pé Roger Hallam àti awọn ajọgbésùnmọ̀mí rẹ̀ jẹ̀bi dídá ìrúkèrúdò sílẹ̀ ní àwùjọ nípasẹ̀ ìdájọ́ ti ìsọ̀kan . Ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù keje, ní Southwark Crown Court, Hallam di dídájọ́ ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún fún nígbà tí àwọn olùjẹ̀bi mẹ́rin mìíràn kọ̀ọ̀kan gba ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rin . [2] [33]
Oníròyìn UN fún àwọn olùgbèjà àyíká , Michel Forst, lo àkókò níbi ìgbẹ́jọ́ náà àti pé ó ṣe pàtàkì fún àwọn ìlànà náà. [33] Àwọn èèyàn pàtàkì pẹ̀lú olùsọ̀rọ̀ TV àti onímọ̀ àyíká Chris Packham, alásè TV Hugh Fearnley-Whittingstall, oníṣòwò Dale Vince, Green Party ẹgbẹ́jẹgbẹ́ Jenny Jones àti Labor Party Norwich South MP Clive Lewis sọ jáde lòdì sí ìdájọ́ náà. [34] Ní ìdàkejì, Andrew Tettenborn, olùkọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti ìmọ̀-òfin ní Yunifásítì Swansea, sọ̀rọ̀ ní Ìsègbè fún ìdájọ́ Hallam.
Ìjọba kọ̀ láti sọ nǹkan kan lórí ìdájọ́ náà, pẹ̀lú agbẹnusọ fún adarí ìgbìmọ̀ ìjọba ti sọ pé “àwọn ìdájọ́ àti ìdájọ́ jẹ́ fún àwọn onídàájọ́ Olómìnira láti ṣe”. Bákan náà ni agbẹnusọ fún ọ́fíìsì agbẹjọ́rò gbogbogbò sọ pé "Àwọn ìpinnu láti ṣe ẹjọ́, ìdálẹ́bi àti ìdájọ́ jẹ́ , ní òtítọ́, ṣe ni òmìnira tí ìjọba nípasẹ̀ Iṣẹ́ ìdájọ́fúnni olórí, àwọn adájọ́ àti àwọn onídàájọ́ lẹ́sẹẹsẹ. Agbẹjọ́rò gbogbogbò kò ní agbára láti dá sí i.” [35]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Empty citation (help)
- ↑ 2.0 2.1 2.2 Empty citation (help)
- ↑ 3.0 3.1 Leake, Jonathan (25 November 2018). "Meet Dr Demo, the activist behind the road-block radicals". https://www.thetimes.co.uk/article/meet-dr-demo-the-activist-behind-the-road-block-radicals-nzd6dsp5k. Retrieved 30 June 2019.
- ↑ Knight, Sam (21 July 2019). "Does Extinction Rebellion Have the Solution to the Climate Crisis?". https://www.newyorker.com/news/letter-from-the-uk/does-extinction-rebellion-have-the-solution-to-the-climate-crisis. Retrieved 22 September 2019.
- ↑ 5.0 5.1 Gayle, Damien (18 October 2023). "Greta Thunberg charged with public order offence after London oil protest". London, United Kingdom. https://www.theguardian.com/uk-news/2023/oct/18/greta-thunberg-charged-with-public-order-offence-after-london-oil-protest. Retrieved 18 October 2023.
- ↑ Dracott, Edd (24 June 2022). "Climate protesters will block roads 'day after day' in October, says XR founder". https://www.standard.co.uk/news/uk/roger-hallam-government-just-stop-oil-london-insulate-britain-b1008307.html.
- ↑ Albery, Nicholas (1992) (in en). The Book of Visions: An Encyclopaedia of Social Innovations. Virgin. ISBN 9780863696015. https://books.google.com/books?id=HN_wAAAAMAAJ. Retrieved 25 March 2019.
- ↑ Taylor, Diane (25 June 2020). "Extinction Rebellion activists launch UK Beyond Politics party by stealing food" (in en). https://www.theguardian.com/environment/2020/jun/25/uk-extinction-rebellion-activists-launch-beyond-politics-party-by-stealing-food. Retrieved 27 August 2020.
- ↑ Birmingham Mail Tuesday 20 March 1990, page 20
- ↑ Birmingham News Thursday 6 January 1994, page 7
- ↑ Birmingham Post Thursday 12 January 1995, page 32
- ↑ 12.0 12.1 12.2 Laville, Sandra; agencies (9 May 2019). "Extinction Rebellion founder cleared over King's College protest". The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/environment/2019/may/09/extinction-rebellion-founder-cleared-over-kings-college-protest. Retrieved 30 June 2019. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "guardian-laville" defined multiple times with different content - ↑ 13.0 13.1 Nye, Catrin (10 April 2019). "The climate protesters who want to get arrested". BBC. https://www.bbc.com/news/science-environment-47865211. Retrieved 30 June 2019.
- ↑ Taylor, Matthew (27 December 2017). "'We don't have time to wait and see': air pollution protesters resort to direct action". The Guardian. https://www.theguardian.com/environment/2017/dec/27/we-dont-have-time-to-wait-and-see-air-pollution-protesters-resort-to-direct-action. Retrieved 27 August 2019.
- ↑ "Anti-Pollution Activists Shut Down Busy London Road During Rush Hour". HuffPost UK. 1 November 2017. https://www.huffingtonpost.co.uk/entry/anti-pollution-activists-marylebone-road_uk_59f99fdbe4b0d1cf6e918072. Retrieved 27 August 2019.
- ↑ Whipple, Tom (1 January 2018). "Clean-air activists hope to be jailed for protests". The Times. https://www.thetimes.co.uk/edition/news/clean-air-activists-hope-to-be-jailed-for-protests-twg5p38sq#. Retrieved 27 August 2019.
- ↑ Carrington, Damian (7 November 2017). "UK government sued for third time over deadly air pollution". The Guardian. https://www.theguardian.com/environment/2017/nov/07/uk-government-sued-for-third-time-over-deadly-air-pollution.
- ↑ Taylor, Matthew (26 October 2018). "'We have a duty to act': hundreds ready to go to jail over climate crisis". The Guardian. https://www.theguardian.com/environment/2018/oct/26/we-have-a-duty-to-act-hundreds-ready-to-go-to-jail-over-climate-crisis. Retrieved 30 June 2019.
- ↑ "European Election 2019: UK results in maps and charts | BBC News". bbc.co.uk. https://www.bbc.co.uk/news/uk-politics-48403131. Retrieved 1 July 2019.
- ↑ "Extinction Rebellion: Roger Hallam calls Holocaust "just another fuckery in human history"". 20 November 2019. https://www.zeit.de/wirtschaft/2019-11/extinction-rebellion-co-founder-roger-hallam-holocaust.
- ↑ "Extinction Rebellion founder's Holocaust remarks spark fury". 20 November 2019. https://www.theguardian.com/environment/2019/nov/20/extinction-rebellion-founders-holocaust-remarks-spark-fury.
- ↑ Boycott-Owen, Mason (3 November 2021). "Extinction Rebellion founder's repugnant rant: 'Climate crisis will lead to gang rape'". The Daily Telegraph. https://www.telegraph.co.uk/news/2021/11/03/extinction-rebellion-co-founder-claimed-climate-crisis-will/.
- ↑ Backes, Laura (22 November 2019). "'We Are Engaged in the Murder of the World's Children'". Der Spiegel. https://www.spiegel.de/international/europe/interview-with-extinction-rebellion-co-founder-roger-hallam-a-1297789.html.
- ↑ 24.0 24.1 "Eco protesters 'caused £7,000 damage to walls at King's College London'". 8 May 2019. https://www.thetimes.co.uk/article/eco-protesters-caused-7-000-damage-to-university-walls-k0k2n8bd3. Retrieved 30 June 2019.
- ↑ "Extinction Rebellion: the arrestables – a photo essay". 7 October 2019. https://www.theguardian.com/environment/2019/oct/07/extinction-rebellion-arrestables-photo-essay. Retrieved 17 October 2019.
- ↑ "Jury clears spray-paint activists from Extinction Rebellion". 10 May 2019. https://www.thetimes.co.uk/article/jury-clears-spray-paint-activists-from-extinction-rebellion-xbjnhzflv. Retrieved 30 June 2019.
- ↑ Gayle, Damien (12 September 2019). "Heathrow third runway activists arrested before drone protest". The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/environment/2019/sep/12/heathrow-third-runway-activists-arrested-before-drone-protest. Retrieved 12 September 2019.
- ↑ "Extinction Rebellion co-founder arrested at Heathrow protest". The Guardian. 14 September 2019. https://www.theguardian.com/environment/2019/sep/14/extinction-rebellion-co-founder-arrested-at-heathrow-protest. Retrieved 16 September 2019.
- ↑ Sharman, Jon (16 September 2019). "Extinction Rebellion co-founder charged over Heathrow drone plot – 'Airport expansion constitutes a crime against humanity,' says Roger Hallam". The Independent. https://www.independent.co.uk/news/uk/crime/extinction-rebellion-heathrow-drones-protest-roger-hallam-a9107686.html. Retrieved 17 September 2019.
- ↑ "Extinction Rebellion Heathrow activist sentenced over drone plan". BBC News. 5 April 2024. https://www.bbc.co.uk/news/uk-england-london-68739970.
- ↑ Gayle, Damien (11 July 2024). "Just Stop Oil activists found guilty of conspiring to block M25 traffic". The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/uk-news/article/2024/jul/11/just-stop-oil-activists-found-guilty-of-conspiring-to-block-m25-traffic.
- ↑ Siddique, Haroon (11 July 2024). "What restrictions are placed on defendants in climate protest trials?". The Guardian. https://www.theguardian.com/law/article/2024/jul/11/climate-protest-trials-evidence-restrictions-m25-activists.
- ↑ 33.0 33.1 33.2 Gayle, Damien (12 July 2024). "Contempt, gagging and UN intervention: inside the UK's wildest climate trial". The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/environment/article/2024/jul/12/contempt-gagging-un-intervention-uk-wildest-climate-trial-just-stop-oil. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "gayle-jso-trial-2-2024" defined multiple times with different content - ↑ Gayle, Damien (19 July 2024). "Celebrities add voice to outcry over severity of Just Stop Oil sentences". https://www.theguardian.com/environment/article/2024/jul/19/chris-packham-celebrities-outcry-over-severity-just-stop-oil-sentences.
- ↑ Gayle, Damien; Horton, Helena; Quinn, Ben (19 July 2024). "'Not acceptable in a democracy': UN expert condemns lengthy Just Stop Oil sentences". The Guardian. https://www.theguardian.com/environment/article/2024/jul/19/not-acceptable-un-expert-condemns-sentences-given-to-just-stop-oil-activists.