Rotimi Salami
Rotimi Salami | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | Lagos State University, New York Film Academy |
Ìgbà iṣẹ́ | 2007—present |
Olólùfẹ́ | Jumoke Salami |
Awards | Africa Magic Viewers' Choice Awards |
Rotimi Salami ( listen) jẹ́ òṣèrékùnrin àti olùṣàgbéjáde fíìmù tó ti fìgbà kan gba àmì-ẹ̀yẹ Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA).[1][2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti Lagos State University, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa sociology. Ó gba ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ ni New York Film Academy.[4]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ọdún 2007, níbi tí ó ti ṣe ìfarahàn rẹ̀ àkọ́kọ́ nínú fíìmù Unknown Revenge, lẹ́yìn náà ni ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán. Fíìmù rẹ̀ àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí i olùdarí eré ni Kuti's career Palace.[5]
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Jumoke Salami ní ọdún 2015, wọ́n sì jọ bí ọmọ méjì.[6][5][7]
Àtọ̀jọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bí i Tinsel, Superstory, Silent Night, About to Wed, Dear Mother, Kuti's Career Palace, Emerald, Alan Poza, Bella's Place, Leave My Boyfriend, 11th Hour, Papa Ajasco, Crack in the Wall;[8] àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn fíìmù mìíràn tí ó ti kópa nínú ni:
- Omoye (2017) bíi Femi
- Shadow Parties (2021) bíi Akinola
- Just Not Married (2016) bíi Lati
- Mirage (2019)
- Divorce Not Allowed (2018) bíi Joe
- Fate of Alakada (2020) bíi Lucky Accessbet
- The Lost Heir (2018)
- Diary of a Crazy Nigerian Woman (2017) bíi Chibuzor
- More Than Just Four Letters (2020)
- Timeless (2017)
- African Queen (2018)
- Unbroken (2018)
- Lugard (2021) bíi Usman
- Stormy Hearts (2017)
- The Miracle Center (2021)
- The Oap (2017)
- Mentally (2017) bíi Udi
- Rancor (2016)
- Enemy Within (1994)
- A Night Before (2015)
- Hey You (2022) bíi Lanre
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Online, Tribune (11 June 2022). "My AMVCA outfit gave me the publicity I wanted —Rotimi Salami". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 July 2022.
- ↑ "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Why I don't lie to women –Nollywood actor, Rotimi Salami". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 June 2022. Retrieved 20 July 2022.
- ↑ "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ 5.0 5.1 "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Actor Rotimi Salami, wife celebrate 7th wedding anniversary - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 July 2022.
- ↑ "My marriage... with actor Rotimi Salami". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 May 2022. Retrieved 16 July 2022.
- ↑ "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]