Jump to content

Rumanatu Tahiru

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Rumanatu Tahiru
Personal information
Ọjọ́ ìbíọjọ kẹrin Osù kẹfà ọdún 1984
Playing positionIwájú
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Athleta Ladies
National team
Ghana2(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 18 March 2017

Rumanatu Tahiru tí a bí ní ọjọ kẹrin Osù kẹfà ọdún 1984 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gba ọmọ orílẹ̀-ède Ghana tí ó seré lókè-òkun tí ó mú ipò iwájú lórí pápá. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìrin orílẹ̀-ède Ghana. Ó wà lára àwọn tí ó kópa ní bi FIFA Women's World Cup ti ọdún 2007 . Lórí ìpele ẹgbẹ́ ó ṣeré fún Athleta Ladies ní Ghana. [1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Empty citation (help) 

Àdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World Cup