Sámúẹ́lì Johnson (ọmọ Yorùbá)
Ìrísí
Fún ẹlòmíràn tóúnjẹ́ Samuel Johnson, ẹ lọ sí Samuel Johnson (ìṣojútùú).

Samuel Johnson (24 June 1846 - 29 April 1901) je alufa ijo Anglikani omo Yoruba ti o ko itan Yoruba pelu akole A History of the Yorubas from the Earliest Times to the Beginning of the British Protectorate ti won tejade ni odun 1921 leyin iku re.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |