Sabrina Draoui
Ìrísí
Sabrina Draoui | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kọkànlá 1977 Batna, Algeria |
Orílẹ̀-èdè | Algerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Science and Technology Houari Boumediene |
Iṣẹ́ | Film director, photographer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008-present |
Sabrina Draoui (tí wọ́n bí ní 24 Oṣù Kọkànlá, Ọdún 1977) jẹ́ olùdarí eré àti olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Àlgéríà.