Saint George SC

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Saint George S.C.
Adis Ababa Stadium
Full nameSaint George Sports Club
Nickname(s)ፈረሰኞቹ (The Horsemen)
አርበኛው (The Patriot)
አራዶቹ (The Aradas)
ሳንጃው (The Bayonet)
Founded1935 (1928 E.C.)
GroundAddis Ababa Stadium
(Capacity: 35,000)
ChairmanAto Abinet Gebremeskel
ManagerZerihun Shengeta
LeagueEthiopian Premier League
2022-23Premier League 1st of 13
WebsiteClub home page
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Home colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Away colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Team colours
Third colours

Saint George Sports Club (Amharic : ቅዱስ ጊዮርጊስ ስፖርት ክለብ, Kidus Giorgis Sport Club), ti inagijẹ rẹ ń jẹ Kidus Giorgis, jẹ ogbontarjgi ẹgbẹ agbabọọlu afẹsẹgba kan ti a da silẹ ni Addis Ababa, Ethiopia. Ẹgbẹ yí ń gba bọọlu ni ipele oke ti bọọlu afẹsẹgba ajumọṣe tí Itiopia (Premier League Ethiopia) . Ti a da ni ọdun 1935, ẹgbẹ naa jẹ akọkọ ni Itiopia ati pe o ti fi idi mulẹ gẹgẹbi aami àtakò ti orilẹ-ede Etiopia tí ó lodi si awọn agbara gbigba tí Fási Ítálì (fascist Italy) .[1]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Aynshet, Solomon (March 11, 2017). "St. George’s Sport Academy to be inaugurated". waltainfo. http://www.waltainfo.com/index.php/news/detail/28117. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]