Jump to content

Samuel Adeleye Adenle

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oba Samuel Adeleye Adenle I
Ataoja of Osogbo

Reign 1933-1944
Spouse Mrs Deborah Adedoyin
Born 1903
Died 1976
Burial Osogbo

Samuel Adeleye Adenle I (1903-1976) jẹ ọba ni ilé Yorùbá . oje Ataoja okandinlogun (Ọba) ti Osogbo ìlú isembaye ti oje olu ìlú ìpínlè Osun.

Igbesi aye ibẹrẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àbí Oba Samuel ni ọdún 1903 wọn dé ni adé gẹ́gẹ́ bíi ọba Ataoja okandinlogun fún ìlú Osogbo ní oṣù kẹrin ọdún 1944 ti òsì di olóògbé ni ọdún 1976. oje ọkọ olórí Deborah Adedoyin o bi ọmọ nígbà aye rẹ[1]

  1. "Evergreen and Loving memory of Adenle".