Sandy Dennis

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sandy Dennis nínú fiimu Up the Down Staircase (odun 1967) trailer 1
Sandy Dennis
Fáìlì:Sandy Dennis.jpg
Ọjọ́ìbíSandra Dale Dennis
(1937-04-27)Oṣù Kẹrin 27, 1937
Hastings, Nebraska, U.S.
AláìsíMarch 2, 1992(1992-03-02) (ọmọ ọdún 54)
Westport, Connecticut, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1956–1991
Alábàálòpọ̀Gerry Mulligan (1965–1974)
Eric Roberts (1980–1985)

Sandra Dale Dennis (Oṣù kẹrin ọjọ́ kẹta-dín-lọ́gbọ̀n, ọdún 1937 sí Oṣù kẹta ọjọ́ kejì, ọdún 1992) jẹ́ òṣèré obìnrin ti Ilẹ̀ Amẹ́ríkà. Ó ṣe àṣeyọrí nínú fíìmù tó gbé e jáde, "Splendor in the Grass" (ọdún 1961). Fún iṣẹ́ rẹ̀ nínú fíìmù eré dírámà àpanilẹ́rìn-ín "Who's Afraid of Virginia Woolf?" (ọdún 1966), ó gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ fún òṣèré àtìlẹ́yìn obìnrin tó dára jùlọ.

Dennis farahàn nínú àwọn fíìmù wọ̀nyí : The Three Sisters (ọdún 1966), Up the Down Staircase (ọdún 1967), That Cold Day in the Park (ọdún 1969), The Out-of-Towners (ọdún 1970), God Told Me To (ọdún 1976), The Four Seasons (ọdún 1981), Come Back to the Five and Dime, Jimmy Dean (ọdún 1982), àti Another Woman (ọdún 1988). Fíìmù tó farahàn gbẹ̀yìn wá ní dírámà adágún "The Indian Runner" (ọdún 1991).

Dennis ní iṣẹ́ àṣeyọrí nínú iṣẹ́ rẹ̀ lórí ìtàgé, ìfarahàn ṣíṣe eré ìtàgé gangan ti "Come Back to the Five and Dime, Jimmy Dean. Fún iṣẹ́ rẹ̀ nínú jara"A Thousand Clowns, ó gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ Tony fún òṣèré obìnrin tó farahàn tó dára jùlọ. Fún iṣẹ́ rẹ̀ nínú eré"Any Wednesday", ó gba ẹ̀bùn àmì ẹ̀yẹ Tony fún òṣèré obìnrin tó dára jùlọ nínú eré náà

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Dennis ní Hastings, Nebraska, ọmọ Yvonne (née Hudson), tó jẹ́ èyí tí àwọn òyìnbó ń pè ní "Secretary", pẹ̀lú Jack Dennis, èyí tí àwọn òyìnbó máa ń pè ní "Postal clerk".[1][2] Ó ní ẹ̀gbọ́n ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Frank. Dennis dàgbà ní Kenesaw, Nebraska, àti Lincoln Nebraska, tí ó jáde láti Ilé-ìwé gíga Lincoln High School ní ọdún 1955; ọ̀kan nínú àwọn ọmọ tí wọ́n jọ wà ní kíláàsì jẹ́ akọ̀wé pẹ̀lú apanilẹ́rìn-ín, Dick Cavett.[3] Ó lọ sí Fásìtì Nebraska Wesleyan àti Fásìtì ti Nebraska, fífarahàn nínú ẹgbẹ́ ìtàgé Lincoln kí ó tó di pé ó kó lọ New York ní ọjọ́ orí ọ̀kàn-dín-lógún.[4] Ó kọ́ eré ṣíṣe ní HB Studio[5] ní Ilẹ̀ New York.

Ikú Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Sandy Dennis kú nípasẹ̀ àìsàn ara kan tí òyìnbó ń pè ní "ovarian cancer" ní oṣù kẹta ọjọ́ kejì, ọdún 1992, ní ilé rẹ̀ ní Westport, Connecticut, ní ọjọ́ orí ẹ̀rìn-lé-láàdọ́ta.[6]

Àwọn Iṣẹ́ Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fíìmù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Title Role Notes
1961 Splendor in the Grass Kay
1966 Who's Afraid of Virginia Woolf? "Honey" Academy Award for Best Supporting Actress
Laurel Award for Top Female Supporting Performance
Laurel Award for Top Female New Face
Nominated—Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture
Three Sisters, TheThe Three Sisters Irina
1967 Up the Down Staircase Sylvia Barrett Moscow International Film Festival Best Actress Award (tied with Grynet Molvig for A Time in the Sun)
Fox, TheThe Fox Jill Banford
1968 Sweet November Sara Deever
1969 Touch of Love, AA Touch of Love Rosamund Stacey
That Cold Day in the Park Frances Austen
1970 The Out of Towners Gwen Kellerman Nominated—Golden Globe Award for Best Actress – Motion Picture Musical or Comedy
Nominated—Laurel Award for Top Female Comedic Performance
1975 Mr. Sycamore Jane Gwilt
1976 God Told Me To Martha Nicholas
1977 Nasty Habits Sister Winifred
1981 Four Seasons, TheThe Four Seasons Anne Callan
1982 Come Back to the 5 & Dime, Jimmy Dean, Jimmy Dean Mona
1986 Laughter in the Dark Unknown
1988 Another Woman Claire
976-EVIL Aunt Lucy Wilmoth
1989 Parents Millie Dew
1991 Indian Runner, TheThe Indian Runner Mrs. Roberts Final film role

Tẹlifísàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Title Role Notes
1956 Guiding Light Alice Holden Unknown episodes
1962 Naked City Eleanor Ann Hubber Episode: "Idylls of a Running Back"
1963 Naked City Lorraine Episode: "Carrier"
Fugitive, TheThe Fugitive Cassie Bolin Episode: "The Other Side of the Mountain"
1964 Arrest and Trial Molly White Episode: "Somewhat Lower Than the Angels"
Mr. Broadway Patricia Kelsey Episode: "Don't Mention My Name in Sheboygan"
1968 Hatful of Rain, AA Hatful of Rain Celia Pope Television film
1970 Only Way Out Is Dead Dr. Enid Bingham Television film
1972 Something Evil Marjorie Worden Television film
1978 Police Story Sharon Bristol Episode: "Day of Terror... Night of Fear"
Perfect Gentlemen Sophie Rosenman Television film
1980 Wilson's Reward Martha James Television film
1985 Execution, TheThe Execution Elsa Spahn Television film
Love Boat, TheThe Love Boat Gina Caldwell Episode: "Roommates/Heartbreakers/Out of the Blue"
Alfred Hitchcock Presents Helen Episode: "Arthur, or the Gigolo"
Young People's Specials Patricia Benson Episode: "The Trouble with Mother"
1986 Equalizer, TheThe Equalizer Kay Wesley Episode: "Out of the Past"

Àwọn Ìtọ́ka Sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Peter Shelley (8 November 2013). Sandy Dennis: The Life and Films. McFarland. ISBN 978-1-4766-0589-0. https://books.google.com/books?id=fd-xAQAAQBAJ&pg=PA1955. 
  2. "The Hour - Google News Archive Search". 
  3. Lincoln High School (1955). The Links, vol. 39. Lincoln, NE: Lincoln High School. p. 38. 
  4. Sandy Dennis. Yahoo Movies.
  5. HB Studio Alumni
  6. Daniels, Lee A. "Sandy Dennis, Veteran Actress And Prize Winner, Is Dead at 54" The New York Times, March 5, 1992