Sarah Ladipo Manyika
Ìrísí
Sarah Ladipo Manyika | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kẹta 1968 Nigeria[1][2] |
Iṣẹ́ | Novelist, short-story writer, essayist, literary critic |
Citizenship | United Kingdom |
Ẹ̀kọ́ | University of Birmingham; University of Bordeaux; University of California, Berkeley |
Genres | Novels, essays, academic papers, book reviews, short stories |
Notable works | In Dependence (2008); Like A Mule Bringing Ice Cream To The Sun (2016) |
Website | |
sarahladipomanyika.com |
Sarah Ladipo Manyika (bíi ni ọjọ́ keje oṣù kẹta ọdún 1968) jẹ́ onkọ̀we ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni olùkọ̀wé In Dependence[3][4] (2009) àti Like A Mule Bringing Ice Cream to the Sun[5][6] [7](2016). Òun ní olóòtú fún ilé iṣẹ́ OZY.[8] Ìwé Manyika farahàn nínú ìtàn àkọlé àwọn ọmọbìnrin títún ní ilẹ̀ Áfríkà.[9]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Sarah Manyika sí ìlú Nàìjíríà. Ó ti gbé ní orílẹ̀ èdè Kenya, France, Zimbabwe àti Britain. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìlú Ìbàdàn. Manyika gboyè jáde láti ọ̀dọ̀ yunifásítì tí Birmingham ní orílẹ̀ èdè UK.
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àṣàyàn àwọn ìwé tí ó ti kọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- In Dependence[10]
- Like A Mule Bringing Ice Cream To The Sun [11]
- Mr Wonder
- The Ambas
- Coming of Age in the Time of the Hoodie".[12]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Sarah Ladipo Manyika". Ohio State University Libraries. Retrieved 13 March 2015.
- ↑ "My Life, My Writings". P.M. News (Nigeria). 26 March 2014. http://www.pmnewsnigeria.com/2014/03/26/my-life-my-writings/. Retrieved 13 March 2015.
- ↑ Beaven Tapureta, "Sarah Manyika's debut novel thrills", The Herald (Zimbabwe), 1 April 2015.
- ↑ "JAMB Introduces New Novel For 2017 UTME Candidates which the students enjoy since for the past few years they've been reading The Last Days At Forcados High School a novel that was also published by Cassava Republic press – 'In Dependence'" Archived 2017-04-06 at the Wayback Machine., Nigeria Today, 14 March 2017.
- ↑ Anna Leszkiewicz, "'Erotic dreams about a man half my age': Sarah Ladipo Manyika reveals the value of pleasure", New Statesman, 3 November 2016. Retrieved 6 November 2016.
- ↑ "The full shortlist", The Goldsmiths Prize 2016, Goldsmiths, University of London.
- ↑ Ainehi Edoro, "Why it Matters that Sarah L. Manyika is on the Goldsmiths Prize Shortlist", Brittle Paper, 10 October 2016.
- ↑ Sarah Ládípọ̀ Manyika biography at OZY.
- ↑ "Photos from the London Launch of Margaret Busby’s New Daughters of Africa Anthology", Brittle Paper, 9 March 2019.
- ↑ In Dependence at Amazon.
- ↑ Like A Mule Bringing Ice Cream To The Sun, Cassava Republic Press, 2016.
- ↑ Sarah Ladipo Manyika, "Coming of Age in the Time of the Hoodie", Guernica, 23 June 2015.
- ↑ Sarah Ladipo Manyika, "Betting on Africa", Brittle Paper, 28 March 2016.
- ↑ Sarah Ládípọ̀ Manyika, "For the Love of Older Characters in Good Books", OZY, 29 October 2017.
- ↑ Sarah Ládípọ̀ Manyika, "Game of Tomes: The Struggle for Literary Prizes", OZY, 2 November 2017.
- ↑ Sarah Ladipo Manyika, "On Meeting Toni Morrison", Transition, No. 124, Writing Black Canadas (2017), pp. 138–147. Indiana University Press/Hutchins Center for African and African American Research at Harvard University.
- ↑ Sarah Ladipo Manyika, "What James Baldwin Means To Me", Brittle Paper, 4 March 2019.
- ↑ Sarah Ladipo Manyika, "On Meeting Mrs Obama", Granta 146: The Politics of Feeling, 22 March 2019. Retrieved 25 March 2019.