Seal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Seal
Seal in Sydney, 2012
Seal in Sydney, 2012
Background information
Orúkọ àbísọHenry Olusegun Adeola Samuel
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiSealhenry Samuel[1][2]
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kejì 1963 (1963-02-19) (ọmọ ọdún 59)
Paddington, London, England
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer-songwriter
  • record producer
Years active1987–present
Labels
Associated acts
Seal
Olólùfẹ́
Heidi Klum
(m. 2005; div. 2014)
Àwọn ọmọ4
AwardsFull list
Websiteseal.com

Henry Olusegun Adeola Samuel[3][4] (ọjọ́ìbí 19 February 1963), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ bíi Seal, ni akọrin àti olùdá-orin ará Brítánì.[5] Àwo orin rẹ̀ ti tà tó 20 millionu àwo orin káàkiri àgbáyé,[6] pẹ̀lú orin rẹ̀, "Crazy", tó gbéjáde ní ọdún 1991; àti "Kiss from a Rose", tó gbéjáde ní ọdún 1994.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]