Jump to content

Shafkat Bose Adewoyin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Shafkat Bose Adewoyin
Aláìsí(2020-06-23)23 Oṣù Kẹfà 2020
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Actress
Gbajúmọ̀ fúnMadam Tinubu

Shafkat Bọ́sẹ̀ Adéwoyin tí ó papò dà ní 23 Oṣù Kẹfà, Ọdún 2020 jẹ́ òṣèré Nollywood ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Madam Tinubu nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Efunroye Tinubu . Adéwoyin kópa nínu àwọn eré orí ìpele bíi ORÍ . Ó tún ti kópa gẹ́gẹ́ bi “Mama Oni” pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Adebayo Salami nínu eré Fúnkẹ́ Akíndélé kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Omo Ghetto.[2][3]

Bọ́sẹ̀ ṣaláìsí ní Ọjọ́ Kẹtàlélógún, Oṣù Kẹfà Ọdún 2020.[4][5][6]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]