Shafy Bello-Akinrimisi
Appearance
Shafy Bello | |
---|---|
Àwòrán lati inu fiimu' Fishbone | |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Shafy Bello-Akinrimisi |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1990s – present |
Àwọn ọmọ | 2 |
Shafy Bello tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ òṣèrébìnrin àti olórin. Orin kíkọ ni ó fi kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ níbi tí ó ti farahàn nínú orin Seyi Sodimu tí "Love Me Jeje" jẹ́ àkọ́lé rẹ̀ ni ọdún 1997.[1][2][3]
Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìlú America ni Shafy dàgbà sí tí ó sì ti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀. Àkọ́lé fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ ni Eti Keta tí ó jẹ́ fíìmù Yorùbá.[4] Ilé ọkọ ni Shafy wà pẹ̀lú ọmọ méjì.[5][6][7]
Ní ọdún 2012, ó ṣe Joanne Lawson nínú fíìmù àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Tinsel, ó sì ṣe Adesuwa nínú Taste of Love. [8] Láti ìgbà náà ni Shafy ti farahàn nínú fíìmù àgbéléwò Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì, díẹ̀ lára wọn ni; When Love Happens, Gbomo Gbomo Express àti Taste of Love.[9][10]
Ààtò àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Eti Keta
- The Score
- Tinsel
- When Love Happens
- Gbomo Gbomo Express
- Taste of Love
- It's Her Day
- Ovy's Voice
- Hire a Man
- Battleground
- Light will Come
- Twisted Twins
- Three Thieves
- Chief Daddy
- From Lagos with Love
- Iboju
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Award ceremony | Prize | Result | Ref |
---|---|---|---|---|
2012 | 2012 Best of Nollywood Awards | Best Lead Actress in an English Movie | Wọ́n pèé | [11] |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Onuoha, Chris (2 August 2015). "There's sexiness in all I do – Shaffy Bello". Vanguard Newspaper. http://www.vanguardngr.com/2015/08/theres-sexiness-in-all-i-do-shaffy-bello/. Retrieved 1 June 2016.
- ↑ "Shaffy Bello : Biography - Filmography - Awards". Flixanda. Archived from the original on 17 September 2021. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "Check out Shaffy Bello & her kids". P.M. News. 2020-01-02. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "‘Dating father and son doesn't mean I’m promiscuous’ -Taste of Love star, Shaffy Bello cries". Ecomium Magazine. 10 August 2015. http://encomium.ng/dating-father-and-son-doesnt-mean-im-promiscuous-taste-of-love-star-shaffy-bello-cries/. Retrieved 1 June 2016.
- ↑ "I Would Have Divorced My Husband- Shaffy Bello". Naij. 14 December 2015. https://www.naij.com/666075-i-would-have-divorced-my-husband-nollywood-actress.html. Retrieved 1 June 2016.
- ↑ "Shafy Bello biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "Shaffy Bello: 7 things you probably didn’t know about the actress". Pulse Nigeria. 2017-10-09. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ Igwegbe, Fola (15 October 2012). "Meet Tinsel's cougar". Africa Magic. http://africamagic.dstv.com/2012/10/15/meet-tinsels-cougar/. Retrieved 1 June 2016.
- ↑ Ekpo, Nathan Nathaniel (14 August 2015). "I'm not a prostitute, I only interpret role...Actress, Shaffy Bello". Nigeria Films. http://www.nigeriafilms.com/news/35074/8/im-not-a-prostitute-i-only-interpret-roleactress-s.html. Retrieved 1 June 2016.
- ↑ "Shaffy Bello: Five Must-Know Facts". Heavyng.Com. 2019-12-09. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ Ehi James, Osaremen (10 September 2012). "Tonto Dikeh, Funke Akindele Others Make BON Award nominees' list". Nigeria Films. Retrieved 1 June 2016.