Jump to content

Ṣakí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Shaki)
Ṣakí Òkè-Ògùn

Ṣakí Òkè-Ògùn
Nickname(s): 
Ọmọ Ṣakí, Ògún 'ó rọ ikin, alágbẹ̀dẹ 'ò rọ bàtà. Ọmọ Àsabàrí 'ò kọ̀' jà, ọmọ Olóógun 'ò k'eré. Tí ó bá d'ọjọ́ ìjà kíá rán ni sí Àsabàrí, tí ó bá d'ọjọ́ eré kíá rán ni sí Olóógun...
Motto(s): 
Shaki-Ọmọ Àsabàrí, akin l'ójú ogun!
Ṣakí Òkè-Ògùn is located in Nigeria
Ṣakí Òkè-Ògùn
Ṣakí Òkè-Ògùn
Location in Nigeria
Coordinates: 8°40′N 3°24′E / 8.667°N 3.400°E / 8.667; 3.400Coordinates: 8°40′N 3°24′E / 8.667°N 3.400°E / 8.667; 3.400
Country Nigeria
OyoStateOyo State
Government
 • GovernorEngr. Oluwaseyi Makinde
 • Okere Of SakilandHRM Ọba Khalid Oyeniyi Olabisi
 • Baagi Of SakilandHigh Chief Ghazali Abdulrasheed
Population
 (2006)
 • Total388,225
 • Ethnicities
Yoruba
 • Religions
Muslim 70%& Christians 30%
Time zoneUTC+1 (WAT)
 • Summer (DST)UTC+1 (not observed)
Websitewww.oyostate.gov.ng

Ṣakí jẹ́ ìlú kan ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,[1]ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilú Ṣakí ni ó wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Agbègbè ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọ̀ Oorun ṢakíÌpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Ibi tí Ìlú Ṣaki wà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn àpáta ńlá ńlá ni wọ́n yí ìlú Ṣaki ká, Ìlú náà wà ní ẹ̀bá odò Ofiki, odò náà sì já sí Odò Ògùn tàbí Ògùnpa ní ǹkan bí ìwọn ogójì kìlómítà

Ìtàn ṣókí nípa Saki láti ẹnu ọmọ bíbí ìlú Saki.

sí ọgọ́ta kìlómítà sí ẹnu ibodè orílẹ̀-èdè olómìnira Benin . Wón sábà ma ń pe Ṣakí ní ''Ilé àgbọ́n ọ̀gbẹ ouńjẹ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́'' látàrí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí wọ́n yàn láàyò.[2]


Àwọn ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Saki - Nigeria". Encyclopedia Britannica. 2013-12-16. Retrieved 2021-06-26. 
  2. <ref name="Tribune Online 2019">"Oke-Ogun, the underdeveloped food basket of the South West". Tribune Online. 2019-02-19. Retrieved 2021-06-26.