Ṣakí
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Shaki, Nigeria)
Ṣakí Òkè-Ògùn Ṣakí Òkè-Ògùn | |
---|---|
Nickname(s): Ọmọ Ṣakí, Ògún 'ó rọ ikin, alágbẹ̀dẹ 'ò rọ bàtà. Ọmọ Àsabàrí 'ò kọ̀' jà, ọmọ Olóógun 'ò k'eré. Tí ó bá d'ọjọ́ ìjà kíá rán ni sí Àsabàrí, tí ó bá d'ọjọ́ eré kíá rán ni sí Olóógun... | |
Motto(s): Shaki-Ọmọ Àsabàrí, akin l'ójú ogun! | |
Coordinates: 8°40′N 3°24′E / 8.667°N 3.400°ECoordinates: 8°40′N 3°24′E / 8.667°N 3.400°E | |
Country | Nigeria |
OyoState | Oyo State |
Government | |
• Governor | Engr. Oluwaseyi Makinde |
• Okere Of Sakiland | HRM Ọba Khalid Oyeniyi Olabisi |
• Baagi Of Sakiland | High Chief Ghazali Abdulrasheed |
Population (2006) | |
• Total | 388,225 |
• Ethnicities | Yoruba |
• Religions | Muslim 70%& Christians 30% |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
• Summer (DST) | UTC+1 (not observed) |
Website | www.oyostate.gov.ng |
Ṣakí jẹ́ ìlú kan ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,[1]ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilú Ṣakí ni ó wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Agbègbè ìjọba Ìbílẹ̀ Ìwọ̀ Oorun Ṣakí ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.
Ibi tí Ìlú Ṣaki wà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn àpáta ńlá ńlá ni wọ́n yí ìlú Ṣaki ká, Ìlú náà wà ní ẹ̀bá odò Ofiki, odò náà sì já sí Odò Ògùn tàbí Ògùnpa ní ǹkan bí ìwọn ogójì kìlómítà
sí ọgọ́ta kìlómítà sí ẹnu ibodè orílẹ̀-èdè olómìnira Benin . Wón sábà ma ń pe Ṣakí ní ''Ilé àgbọ́n ọ̀gbẹ ouńjẹ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́'' látàrí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí wọ́n yàn láàyò.[2]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Saki - Nigeria". Encyclopedia Britannica. 2013-12-16. Retrieved 2021-06-26.
- ↑ <ref name="Tribune Online 2019">"Oke-Ogun, the underdeveloped food basket of the South West". Tribune Online. 2019-02-19. Retrieved 2021-06-26.