Shalewa Ashafa
Ìrísí
Shalewa Ashafa | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Keje 1995 Ìpínlẹ̀ Ogun |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | ShallyStar |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásitì ìpínlẹ̀ Èkó |
Iṣẹ́ | òṣèrébìnrin |
Notable work | The Razz Guy |
Shalewa Ashafa gbó (tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù keje ọdún 1995) tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí ShallyStar jẹ́ òṣèrébìnrin Nollywood tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú eré Ajoche àti The Razz Guy.[1][2]
Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Shalewa Ashafa jẹ́ àbíkẹ́yìn àwọn òbí rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun .[2][3] Ó lọ ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní Christ the Cornerstone Nursery àti Primary School, GRA Ikeja, Èkó ó sì lọ ilé-ìwé Sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ ní Iloko Model College ní ìpínlẹ̀ Osun. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ìpolongo ọjà ní Yunifásítì ìlú Èkó.[1][3][2]
Àtòjọ àwọn fíìmù tí ó ti ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Evol (2017),
There is Something,
The Razz Guy,
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "I’m a fantastic actress - Shalewa Ashafa". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-25. Retrieved 2022-08-03.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 Cyril (2022-02-01). "My talent is my selling point – Omoshalewa". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03.
- ↑ 3.0 3.1 "Getting big roles is sometimes based on who you know — Shalewa Ashafa". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-02. Retrieved 2022-08-03.