Simi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Simi
Àwòrán Simi
Àwòrán Simi
Background information
Orúkọ àbísọSìmísọ́lá Bọ́látitó Ògúnlẹ́yẹ
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiSymplySimi
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹrin 19, 1988 (1988-04-19) (ọmọ ọdún 32)
Surulere, Èkó , Ìpínlẹ̀ Èkó , Nigeria
Irú orin
Occupation(s)Singer-songwriter, vocalist
InstrumentsVocals
Years active2006–present
LabelsX3M
Associated acts

Sìmísọ́lá Bọ́látitó Ògúnlẹ́yẹ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Simí jẹ́ olórinbìrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Àwọn àmìn-ẹ̀yẹ tí ó gbà àti àwọn tí wọ́n yàn án fún[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Ayẹye ẹ̀yẹ Ẹ̀bùn Ẹni tí ó gbàá tàbí tí wọ́n fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀ Èsì Ìtọ́kasí
2015 2015 Nigeria Entertainment Awards Most Promising Act to Watch Fúnra rẹ̀ Gbàá [2]
2015 City People Entertainment Awards Most Promising Act of The Year Gbàá [3]
2015 Nigerian Music Video Awards Best RnB Video "Tiff" Yàán [4]
Music Video of The Year Yàán [4]
Best Soft Rock/Alternative Video "Jamb Question" Yàán [5]
2016 The Headies 2015 Best Alternative Song "Tiff" Yàán [6]
Best Vocal Performance (Female) Herself Yàán [6]
2016 City People Entertainment Awards Female Artiste of the Year Gbàá [7]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]