Simidele Adeagbo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Simidele Adeagbo
OLY
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ àbísọSimidele Adeife Omonla Adeagbo
Ọmọorílẹ̀-èdè
Ọjọ́ìbíOṣù Keje 29, 1981 (1981-07-29) (ọmọ ọdún 42)
Toronto, Ontario, Canada
IbùgbéJohannesburg, South Africa
Height1.70 m (5 ft 7 in)
Weight65 kg (143 lb)
Sport
Orílẹ̀-èdè
Erẹ́ìdárayá
  • Track & Field
  • Skeleton
Event(s)
  • Triple Jump
  • Skeleton
University teamUniversity of Kentucky
Coached byNick Vienneau
Achievements and titles
Regional finals2022 Woman's Monobob World Series; UK Scholar Athlete of the Year, 2003 Indoor Southeastern Triple Jump Champion
National finalsOlympic Trials Finalist 2004 & 2008 (Triple Jump), 4 Time NCAA all American in the Triple Jump and Academic All-American,
Olympic finals20th (Pyeongchang 2018)
Highest world ranking74
Personal best(s)Track and Field (Triple Jump) 13.99m (June 27 th , 2008)

Simidele Adeife Omonla Adeagbo[1] (tí wọ́n bí ní July 29, 1981, sí ìlú Toronto, Ontario, Canada)[2] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje eré-sísá. Ó kópa nínú ìdíje ti 2018 Winter Olympics. Ó jẹ́ ọmọbìnrin Nàìjíríà àti Africa àkọ́kọ́ tó jẹ́ skeleton athlete. Òun sì ní ọmọbìnrin aláwọ̀ dúdú àkọ́kọ́ tó máa kópa nínú eré-ìdárayá Olympic. Ní ọdún 2022, ó jáwé olúborí nínú ìdíje EuroCup ti ọdún 2022, tó wáyé ní ìlú Germany. Látàrí èyí, ó di ọmọ Africa àkọ́kọ́ tó gba jáwé olúborí nínú ìdíje àgbáyé.[3] Kí ó tó kópa nínú ìdíje skeleton, Adeagbo kópa nínú ìdíje triple jump, ní ọdún 2008.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Adeagbo sí ìlú Toronto, ní Ontario, Canada, sínú ìdílé àwọn ọmọ Nàìjíríà. Ó kó lọ sí ìlú Ìbàdàn, ní Nàìjíríà nígbà tí ó wà lọ́mọ́dé, ó sì gbé níbẹ̀ fún ọdún mẹ́fà kí ó tó lọ sí United States.[4]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adeagbo ṣiṣẹ́ fúnNike body double fún Serena Williams.[5] Adeagbo sì jẹ́ alábòójútó ètò ọrọ̀-ajé ti South Africa, láti ọdún 2012.[6]

Ní August 18, 2018, Adeagbo sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ TEDxLagos ní Muson Centre, pẹ̀lú àwọn ènìyàn ńlá mìíràn bí i [7] Supo Shasore, Ade Olufeko, Tokini Peterside àti Banky W.[8]

Àwọn ìdíje rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lórí pápá àti abẹ́lé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

[9]

Event Result Venue Date
Outdoor
100 meters 12.05 (wind: +1.7) Baton Rouge, Louisiana 13 May 2000
100 meters 11.96 (wind: +3.1) Coral Gables, Florida 17 Mar 2001
Long jump 6.20 m A (wind: +0.9 m/s) Eugene, Oregon 19 Jun 2004
Long jump 6.36 m A (wind: +4.9 m/s) Austin, Texas 06 Apr 2001
Triple jump 13.99 m A (wind: +2.0 m/s) Eugene, OR 27 Jun 2008
Indoor
60 meters 7.59 Lexington 13 Jan 2001
Long jump 6.25 m Nampa, Idaho 28 Jan 2005
Triple jump 13.40 m Seattle 28 Jan 2006

Skeleton[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

[10]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Olympians: Olympians for Life – website of the WOA
  2. "Sleigh, Simidele Adeagbo, Sleigh". Nike. 9 January 2018. 
  3. "Nigeria's Adeabgo becomes first African to win international sled race". ESPN.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-17. Retrieved 2022-02-05. 
  4. "Nigerian bobsledder aims for Africa's first Winter Games medal". BBC Sport. 13 February 2023. Retrieved 14 February 2023. 
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named IBSF-bio
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Nike-2018-01-092
  7. "Olasupo Sasore, Bankole Wellington, Simi Adeagbo, others deliver inspiring talks at event co-sponsored by Union Bank". Pulse. Retrieved 17 September 2018. 
  8. Ukiwe, Urenna (16 August 2018). "TEDXLagos Exciting "Spotlight" Set To Hold". The Guardian (Nigeria). Retrieved 17 September 2018. 
  9. "SIMIDELE ADEAGBO". IAAF Athletes. International Association of Athletics Federations. 
  10. "Simidele ADEAGBO". IBSF Athletes. International Bobsleigh and Skeleton Federation. Archived from the original on 2020-11-22. Retrieved 2024-04-16.