Smaranda Olarinde
Ìrísí
Smaranda Olarinde jẹ́ olùkọ́ nínú ìmò òfin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun sì olórí ẹgbẹ́ Nigerian Association of Law Teachers àti VC fún ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Afé Babalolá University.[1][2][3] Ní ọdún 1995, ó ṣiṣẹ́ pẹlu UNICEF.[4][5]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Arábìnrin Olarinde tí ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olùkọ́ ìmò òfin fún ọdún tí ó tí lé ní ọgbọ́n. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Think Tank èyí tí wọn dá fún àbò àwọn ọmọdé ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Òun sì ní adarí fún ẹgbẹ́ International Federation of Women Lawyers. Ọmọ rẹ̀, Ifedayo Olarinde jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí rádíiò Cool Fm.[6][7]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Former minister, others applaud ABUAD’s law programme". Punch News. Archived from the original on February 19, 2015. Retrieved June 5, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigerian Law teachers plan directory". Daily independent. Archived from the original on July 2, 2015. Retrieved June 5, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Deputy Vice Chancellor, Administration". abuad.edu.ng. Retrieved June 5, 2015.
- ↑ "CJN. Seeks end to bad eggs in legal profession". News Nigeria. Archived from the original on July 5, 2015. Retrieved June 5, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "The Provost". abuad.edu.com. Archived from the original on April 7, 2015. Retrieved June 5, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Daddy Freeze introduces his mother: You might be surprised who she is". expressiveinfo.com. July 9, 2019. Retrieved July 10, 2019.
- ↑ "I am not bleaching, Neither was I adopted. Here is a pic of my mum to prove this ~ Freeze". June 20, 2016. Archived from the original on July 1, 2019. Retrieved July 18, 2016.