Sophie Oluwole

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Sophie Bosede Oluwole (bíi ni ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1935) tí orúkọ ìnagi rẹ̀ jẹ́ Iyanifa jẹ́ onímọ̀ ìjìnlè Áfríkà.[1][2] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má gboyè jáde nínú ìmò ìjìnlè ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3][4]

Ayé àti iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Sophie ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn-ún ọdún 1935, ó sì jẹ́ ọmọ ìlú Edo. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Philosophy. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ilé ẹ̀kọ́ náà ní ọdún 1972. Ó kú ní ọjọ́ kẹtàlélógún, oṣù kejìlá ọdún 2018.[5]

Àṣàyàn àwọn iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • (1992) Witchcraft, Reincarnation and the God-Head (Issues in African Philosophy);
  • (1997) Philosophy and Oral Tradition;
  • (2014) Socrates and Ọ̀rúnmìlà: Two Patron Saints of Classical Philosophy;[6]
  • (2014) African Myths and Legends of Gender (with Akin Sofoluwe).

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]