Souleymane Ndéné Ndiaye
Ìrísí
Souleymane Ndéné Ndiaye | |
---|---|
Prime Minister of Senegal | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 30 April 2009 | |
Ààrẹ | Abdoulaye Wade |
Asíwájú | Cheikh Hadjibou Soumaré |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹjọ 1958 Kaolack, Senegal (then a French colony) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Senegalese Democratic Party |
Souleymane Ndéné Ndiaye (ojoibi 6 August 1958[1]) je oloselu ara Senegal to je yiyan gege bi Alakoso Agba ile Senegal ni 30 April 2009. Teletele ohun ni Alakoso fun Onise-oba ati Agbase ni 2005, Oludari fun Kabinet Aare Orile-ede lati 2005 to 2007, ati Alakoso fun Okowo Ori-Omi lati 2007 de 2009.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "NOUVEAU PREMIER MINISTRE : Souleymane Ndéné Ndiaye, un avocat politicien à la primature", Nettali (Seneweb.com), 30 April 2009 (Faransé).