Jump to content

Stanley Ohajuruka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Stanley U. Ohajuruka jẹ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ile ìgbìmò aṣòfin fun ìgbà méjì àti olórí ilé ìgbìmò aṣòfin ìpínlẹ̀ Abia . [1] [2]

Ohajuruka ṣojú fún àwọn àgbègbè Ikwuano, Umuahia North, ati Umuahia South ni ipinle Abia ni ile ìgbìmọ̀ asòfin àgbà gẹ́gẹ́ bi ọmọ ile ìgbìmò aṣofin agba . [3] Samuel Ifeanyi Onuigbo lo gbà ipo yii lo. Bákan naa ni wón tun yan an ni Adele Gómìnà ipinlẹ Abia ni àkókò kan lásìkò òṣèlú re. [4] [5]

Ni Oṣu Kejila ọdun 2024, Aarẹ Bola Tinubu yan Ohajuruka gẹgẹ bi olùdarí eto iṣuna lori ìgbìmò ti South-East Development Commission (SEDC). [6] [7]