Jump to content

Stephen Fagbemi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Stephen Fagbemi
Ọjọ́ìbíOba Ile Ondo state
Ẹ̀kọ́University of Kent

 

Stephen Ayodeji Akinwale Fagbemi jẹ bíṣọ́ọ̀bù [1] ti ìjọ AnglicanNaijiria[2], ó jẹ́ bíṣọ́ọ̀bù ti Owo lọ́wọ́lọ́wọ́.

Wọ́n bí Fagbemi ní Oba-Ilé, Ìpínlẹ̀ Ondo. Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní Immanuel College of Theology and Christian Education, Ibadan àti University of Kent. Leyin curacies ni Owo ati Iyere o je alufaa ni Wakajaye-Etile. He was Vicar of Emure-Ile from 1996 to 2000; and had permission to officiate in the Diocese of Canterbury from 2000 to 2003. Ó ń ṣe àjọṣepọ̀ Chaplain ní Sunderland láti ọdún 2004 sì 2011 ; ati Dean ti Archbishop Vining College of Theology lati 2011 si 2016. Ó jẹ́ akọ̀wé àgbà fún Ìjọ Nàìjíríà láti ọdún 2016 títí di ìgbéga rẹ̀ sí episcopate ní ọdún 2017.

Wọ́n yà á sí mímọ́ gẹ́gẹ́ bíi Bishop of Oyo ní Ṣọ́ọ̀ṣì Cathedral ti St. James ńlá, Oke-Bola, Ìbàdàn, ní ọjọ́ 30 oṣù Keje ọdún 2017. O ṣe ìkìlọ fun ijọba ati awọn eniyan Naijiria lori ipo oselu ati ọrọ aje ni Naijiria.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Anglican Diocese of Owo (19 September 2020). "Position - Nigeria - Diocese of Owo". anglicandioceseofowo.org. Archived from the original on 2021-01-25. Retrieved 2020-11-24. 
  2. "Who are the elect in Peter 1". mooara. Retrieved 2020-11-21. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]