Syed Ahmad Dehlvi
Àdàkọ:Infobox religious biography Ọ̀gbẹ́ni Syed Ahmad Dehlvi (tí wọ́n tún lè kọ báyìí Sayyid Aḥmad Dihlawī; tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kìíní ọdún 1846 – ó kú lọ́jọ́ kọkànlá oṣù karùn-ún ọdún 1918) jẹ́ onímọ̀ ẹ̀sìn Mùsùlùmí, onímọ̀ èdè àti ọ̀rọ̀, onímọ̀ òye, onímọ̀ ẹ̀kọ́, ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè India. Bẹ́ẹ̀ náà, ó jẹ́ oǹkọ̀wé èdè Urdu. Òun ni ó ṣe àtòjọ ìwé atúmọ èdè Asifiya dictionary.
Ìgbésíayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Syed Ahmad Dehlvi lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kìíní ọdún 1846 ní ìlú Delhiní Mughal India.[1][2] Òun ní ọmọ bíbí Ọ̀gbẹ́ni Hafiz Abd al-Rahman Mongheri, tí ó jẹ́ ìran Abdul Qadir Jilani.[3]
Dehlvi ran S W Fallon lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ ìwé atúmọ èdè láàárín ọdún ọdún 1873 sí 1879.[1] He taught at Shahi Madrasa, located in the Arab Sarai, in Delhi.[3] Wọ́n fìgbà kan yàn án ní olùkọ́ èdè Urdu àti Persian ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ní Himachal Pradesh. Ó jẹ́ olùkọ́ pàtàkì àti olùdánwò ní University of the Punjab, bẹ́ẹ̀ náà ó jẹ́ igbákejì Ọ̀gá Government Book Depot ní Lahore.[2]
Lọ́dún 1914, àwọn ìjọba ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì tí wọ́n wà ní India] dá Dehlvi lọ́lá òye Khan Sahib.[3][2] He died on 11 May 1918.[1]
Àwọn iṣẹ́ ọ̀nà lítíréṣọ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Farhang e Asifiya
- Hādi-un-Nisa
- Lughāt-un-Nisā
- ʻIlmullisān : yaʻnī, insān kī ibtidāʼī, darmiyānī aur ak̲h̲īr zabān
- Rusūm-i Dihlī
- Qiṣṣah-yi Mihr Afroz
- Munāẓirah-yi taqdīr-o-tadbīr, maʻrūf bih kunzulfavāʼid.
- Muhakama-e-Markaz-e-Urdu[5]
- Muraqqa-e-Zuban-o-Bayan-e-Dehli[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Parekh, Rauf (29 April 2013). "Farhang-i-Aasifiya: a dictionary reflecting cultural heritage". Dawn. https://www.dawn.com/news/794661/farhang-i-aasifiya-a-dictionary-reflecting-cultural-heritage.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 Asir Adrawi. Tazkirah Mashāhīr-e-Hind: Karwān-e-Rafta. p. 116.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 Lal, Mohan, ed (1992). "SYED AHMAD DEHLAVI". Encyclopaedia of Indian Literature: Sasay to Zorgot. New Delhi: Sahitya Akademi. p. 4262. ISBN 9788126012213. https://books.google.com/books?id=KnPoYxrRfc0C&dq=Syed+Ahmad+Dehlvi&pg=PA4262. Retrieved 3 January 2021.
- ↑ "Profile of Syed Ahmad Dehlvi on WorldCat". WorldCat. Retrieved 3 January 2021.
- ↑ "محاکمۂ مرکزِ اردو" [Muhakama-e-Markaz-e-Urdu]. Urdu Gah.
- ↑ "مرقعِ زبان و بیانِ دہلی" [Muraqqa-e-Zuban-o-Bayan-e-Dehli]. Urdu.
- Asir Adrawi (2 April 2016) (in Urdu). Tazkirah Mashāhīr-e-Hind: Karwān-e-Rafta. Deoband: Darul Muallifeen. p. 116.