Sylvia Plath

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sylvia Plath
Pen nameVictoria Lucas
Iṣẹ́Poet, novelist, and short story writer
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
Ẹ̀kọ́Cambridge University
Alma materSmith College
Ìgbà1960–1963
GenreAutobiography, children's literature, feminism, mental health, roman à clef
Literary movementConfessional poetry
Notable worksThe Bell Jar
Notable awardsFulbright scholarship
Glascock Prize
1955

Pulitzer Prize for Poetry
1982 The Collected Poems

Woodrow Wilson Fellowship
SpouseTed Hughes
ChildrenFrieda and Nicholas Hughes

SignatureFáìlì:Sylvia Plath signature.jpg

Sylvia Plath (October 27, 1932 – February 11, 1963) A bí Plath ní ọdún 1933. Ó kú ní 1963. Ọmọ ilẹ̀ Àmẹ́ríkà ni ṣùgbọ́n Jámànì ni àwọn òbí rẹ̀ ti wá. Nígbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́sàn-án ó ní ‘shock’ nítorí ikú bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú Bàọ́lọ́jì ní University ti Bosston. Gbogbo ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ sí i yìí ni ó ń hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ewì tí ó kọ. Ó ṣiṣẹ́ ní Àmẹ́ríkà àti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Ó fẹ́ akéwì ọmọ ilè Gẹ̀ẹ́sì tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ted Hughes. A Alvarez ni ó tẹ́ ìtàn ikú tí ó kú ní rèwerèwe jáde.




  1. Introduction to Twilight at the Equator: A Novel by Jaime Manrique. University of Wisconsin Press, 2003 ISBN 0-299-18774-8
  2. Journal of Modern Literature, Vol. 1, No. 1 (1970), pp. 57–74