Tòbágò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Tobago
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Tobago
MottoPulchrior Evenit   (Latin)
"She becomes more beautiful"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèForged From The Love of Liberty
OlúìlúScarborough
Èdè àlòṣiṣẹ́ English, Tobago Creole
Ìjọba autonomous island of Trinidad and Tobago
 -  President of Trinidad and Tobago George Maxwell Richards
 -  Chief Secretary Orville London
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 300 km2 
116 sq mi 
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2000 54,000 
Owóníná Trinidad and Tobago dollar (TTD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè (UTC-4)
Àmìọ̀rọ̀ Internet .tt
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 1-868

Tobago (pípè /təˈbeɪɡoʊ/) ni eyi to kerejulo ninu awon erekusu meji niinla to se Orile-ede Olominira ile Trinidad ati Tobago. O budo si apaguusu Omiokun Karibeani, ariwailaorun erekusu Trinidad ati guusuilaorun Grenada. Erekusu yi wa ni ode ile iji.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]