Jump to content

George Maxwell Richards

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
George Maxwell Richards.
George Maxwell Richards

Fáìlì:GeorgeMaxwellRichards.jpg
Aare ile Trinidad ati Tobago
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
17 March 2003
Alákóso ÀgbàPatrick Manning
Kamla Persad-Bissessar
AsíwájúArthur Robinson
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1931 (ọmọ ọdún 92–93)
San Fernando, Trinidad and Tobago
(Àwọn) olólùfẹ́Jean Ramjohn-Richards
Alma materQueen's Royal College
University of Manchester Institute of Science and Technology
Pembroke College, Cambridge
ProfessionChemical Engineer
Chancellor

George Maxwell Richards, TC, CM (born 1931) ni Aare ikerin orile-ede Trinidad and Tobago. Onimo iseero kemika, Richards lo tije Oluko Agba Ogba St. Augustine ti Yunifasiti West Indies ni Trinidad ni 1996. Teletele o tun ti sise fun Shell Trinidad Ltd. ko to dipe o bo si Yunifasiti West Indies ni 1965. O di Aare ni March 17, 2003 fun igba odun marun. Richards ni Olori Orile-ede akoko ni Anglophone Caribbean to je Amerindian.