Patrick Manning
Ìrísí
Patrick Manning | |
---|---|
Manning in 2008. | |
4th & 6th Prime Minister of Trinidad and Tobago | |
In office 24 December 2001 – 26 May 2010 | |
Ààrẹ | Arthur Robinson George Maxwell Richards |
Asíwájú | Basdeo Panday |
Arọ́pò | Kamla Persad-Bissessar |
In office 17 December 1991 – 9 November 1995 | |
Ààrẹ | Noor Hassanali |
Asíwájú | Arthur Robinson |
Arọ́pò | Basdeo Panday |
Member of Parliament for San Fernando East | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1971 | |
Asíwájú | Gerard Montano |
Majority | 10,320 (70.6%) |
Leader of the Opposition | |
In office 6 November 1995 – 24 December 2001 | |
Asíwájú | Basdeo Panday |
Arọ́pò | Basdeo Panday |
In office 1986–1991 | |
Asíwájú | Basdeo Panday |
Arọ́pò | Basdeo Panday |
Leader of the People's National Movement | |
In office 1986–2010 | |
Asíwájú | George Chambers |
Arọ́pò | Keith Rowley |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹjọ 1946 San Fernando, Trinidad and Tobago |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's National Movement |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Hazel Manning |
Alma mater | University of the West Indies |
Profession | Geologist |
Website | Official website |
Patrick Augustus Mervyn Manning (ojoibi 17 August 1946) je oloselu ati Alakoso Agba kerin ati ikefa orile-ede Trinidad ati Tobago tele, bakanna tele ohun lo je olori egbe oselu People's National Movement (PNM)[1]. O di Alakoaso Agba lati 17 December 1991 de 9 November 1995 ati lati 24 December 2001 titi di 26 May 2010. O tun je Olori Olodi lati 1986 de 1990 ati from 1995 to 2001. Ohun nlo je olori egbe oloselu PNM lati 1987 de 2010. O gba eko bi aseorooriile, Manning ti je bi Omo Ileasofin fun agbegbe Ilaorun San Fernando lati 1971, loni ohun ni omo Ile awon Asoju to wa nibe pejulo.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2010-04-25. Retrieved 2011-01-03.
- ↑ Biographical Summary of the Prime Minister of Trinidad and Tobago Archived 2006-05-01 at the Wayback Machine., from NALIS, the National Library and Information Service of Trinidad and Tobago