Taofeek Adaranijo
Ìrísí
Taofeek Abiodun Adaranijo je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. O je ọmọ ile ìgbìmọ̀ aṣojú ìjọba àpapọ̀ to n sójú àgbègbè Agege ti Ìpínlẹ̀ Eko ni ile ìgbìmọ̀ aṣòfin agba kejo. [1] [2]
Adaranijo ni won yan si ile ìgbìmọ̀ asofin gẹ́gẹ́ bi omo ẹgbẹ òṣèlú APC. [3] [4] [5] O ti ṣe alaga ijọba ibilẹ Orile Agege tẹlẹ lati ọdun 2004 si 2014. [6] [7]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://independent.ng/sanwo-olu-hasnt-failed-lagosians-taofeek-adaranijo/hon-taofeek-adaranijo-former-member-federal-house-of-representatives-agege-federal-constituency/
- ↑ https://newsdiaryonline.com/adaranijo-tasks-tinubu-10th-nass-on-recognition-of-lagos-lcdas/
- ↑ https://independent.ng/sanwo-olu-hasnt-failed-lagosians-taofeek-adaranijo/
- ↑ https://guardian.ng/news/house-of-reps-member-elect-promises-not-to-disappoint-constituents/
- ↑ https://www.nationalaccordnewspaper.com/protest-lagos-cant-afford-repeat-of-endsars-pains-apc-chieftain/
- ↑ https://pmnewsnigeria.com/2010/05/26/orile-agege-council-lays-foundation-for-new-office/
- ↑ https://dailypost.ng/2014/12/08/apc-primaries-candidates-emerge-lagos/