Taoreed Lagbaja
Taoreed Lagbaja | |
---|---|
Chief of Army Staff | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 19 June 2023 | |
Ààrẹ | Bola Tinubu |
Asíwájú | Faruk Yahaya |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kejì 1968 Irepodun, Western State, Nigeria (now in Osun State) |
Alma mater | |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Nigerian Army |
Years of service | 1987–2024 |
Rank | Major general |
Ọ̀gágun Major General Taoreed Abíọ́dún Lágbájá (ni wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1968 o si ku ni Oṣu kọkanla ọjọ 5, ọdun 2024) jẹ́ Ọ̀gágun-àgbà tí ó gboyè Major General nínú iṣẹ́ ológun orílẹ̀ - èdè Nigeria. Òun ni Ọ̀gágun-àgbà yányán àwọn ológun Nigeria, Chief of Army Staff.[1][2][3] He was appointed on 19 June 2023 by President Bola Tinubu to succeed Lieutenant General Faruk Yahaya.
Ìgbà èwe rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Lágbájá ní ìlú Ìlobù ní ìjọba Ìbílẹ̀ Ìrẹ́pọ̀dùn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1968. Ó lo ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ní ìlú Òṣogbo, níbi tí ó ti kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní ilé-ìwé St Charles Grammar School and Local Authority Teachers College.[4]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n gbà á sí ilé-ìwé àwọn ológun Nigerian Defence Academy ọdún 1987. Wọ́n fún un lóye ológun (Second Lieutenant) lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1992 ẹgbẹ́ ológun Nigerian Infantry Corps.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ogalla, Abubakar, Egbetokun, Lagbaja, Musa - Meet Nigeria new Service Chiefs". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-65954606.
- ↑ Udeh, StellaO; Aguwa, EmmanuelN; Onwasigwe, ChikaN (2022). "Workplace burnout and psychological health of military personnel in a Nigerian barrack". Nigerian Journal of Medicine 31 (3): 302. doi:10.4103/njm.njm_31_22. ISSN 1115-2613. http://dx.doi.org/10.4103/njm.njm_31_22.
- ↑ Ariemu, Ogaga (2023-06-20). "10 interesting things to know about new COAS, Maj Gen Lagbaja". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-20.
- ↑ 4.0 4.1 Yusuf, Kabir (2023-06-20). "PROFILE: Major General Taoreed Lagbaja: New head of Nigerian Army". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-20.