Tawa Ishola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Tawa Ishola tí a bí ní ọjọ́ Kẹtalélógún oṣù Kejìlá ọdún 1988 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tí ó gbá bọ́ọ̀lù lọ́wọ́ àárín fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin agba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Olimpiiki ní ọdún 2008 . [1]

Wo eyi naa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Orilẹ-ede Naijiria ni Olimpiiki Igba ooru 2008

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help) 

Ita ìjápọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]