Temi Balogun
Ìrísí
Temi Lola Balogun tí orúkọ inagi rẹ̀ jẹ́ TaymiB jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun sì ní olùgbé sílẹ̀ ètò Skinny Girl in Transit. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queen's College ni ìlú Èkó. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Nottingham Trent University[1]. Òun àti àbúrò rẹ̀ jọ kọ orin Soyinka's Afro ní ọdún 2009.[2] Balogun di atọ́kun fún ilé iṣẹ́ Cool Fm ni ìlú Èkó.[3] Ó gbé eré Things Men Say jáde ní ọdún 2017.[4][5] Ní ọdún 2019, òun àti N6 jọ ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ fún olórin Cardi B nígbà tí ó wá sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà[6][7]. Tèmilola jẹ́ ìyàwó fún Timi Akinmuda, wọ́n sì ti bí ọmọ méjì.[8]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Judges - Africa Connected". www.africaconnected.com. Archived from the original on 2020-01-30. Retrieved 2020-02-29.
- ↑ BellaNaija.com (2009-11-05). "Who Is…Soyinka’s Afro". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-29.
- ↑ "Cool FM". Streema. Retrieved 2020-02-29.
- ↑ "Temilola Akinmuda The Creative". guardian.ng. Archived from the original on 2020-02-29. Retrieved 2020-02-29.
- ↑ Tv, Bn (2017-09-19). "It's here! Watch Episode 1 of Box TV's "Things Men Say" featuring Bollylomo & Joules". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-29.
- ↑ "Cool FM hosts Cardi B in first ever live radio interview in Nigeria". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-07. Retrieved 2020-02-29.
- ↑ Salaudeen, Aisha. "Cardi B is set to perform for the first time in Nigeria and Ghana". CNN. Retrieved 2020-02-29.
- ↑ CoolFM, StayBusy Tech For. "Cool FM Nigeria | #1 Hit Music Station". CoolFM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-29.