Jump to content

Temie Giwa-Tubosun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Temie Giwa
Ọjọ́ìbíOlúwalóní Ọlámidé Gíwá
(1985-12-00)Oṣù Kejìlá 1985
Ila Orangun, Osun, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian, American
Orúkọ mírànTemie Giwa, Temie Giwa-Tubosun
Iléẹ̀kọ́ gígaMinnesota State University Moorhead, Middlebury Institute of International Studies at Monterey
Iṣẹ́Health Entrepreneur
Olólùfẹ́Kola Tubosun
Websitelifebank.ng

Oluwaloni Olamide Giwa tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Temie Giwa-Tubosun (tí a bí ní oṣù Kejìlá ọdún 1985) jé ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà mọ́ Amẹ́ríkà tí ó ní ìmò nípa ètò ìlera, òun ní ọ̀lùdásílẹ̀ Life Bank(ilé-isé tí wón ń pè ní One Percent Project), ilé-isé kan ní Nàìjíríà tí ó ń síse takuntakun láti ri si ilo wọ́rọ́wọ́ ètò Ìfún ni lẹ́jẹ̀ ní Nàìjíríà.[1][2][3][4]

  1. "Blood shortage a huge problem in Nigeria". The Nation. 8 April 2016. 
  2. "For One Percent: An Innovative Blood Bank in Nigeria". Nigerian Health Watch. 25 August 2015. 
  3. "How innovative Mobile App is saving lives by connecting blood donors & recipients". Nigerian Health Watch. 28 August 2015. Archived from the original on 24 April 2016. Retrieved 11 February 2023. 
  4. "Temie wins Netpreneur award". TheAfricanDream.net. 17 November 2019.