Jump to content

Tempoe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Michael Chigozie Alagwu, tí prúkọ ìtàgé rẹ̀ ń jẹ́ Tempoe, jẹ́ agbórinjáde , ó tún jẹ́ Dj, akọrin àti ònkọrin , ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí i ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó di gbajúmọ̀ látàrí ìpèdè rẹ̀ MAD tí ó ma ń sọ ní ìbẹ̀rẹ̀ tàbí ìparí Orin rẹ̀. Orin CKay tí ó jẹ́ Afrobeat tí ó gbé jáde tí àkọ́lé rẹ̀re ń jẹ́ Love Nwantiti ni ó sọ ọ́ di ìlúmọ̀ọ́ká.

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tempoe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ statistíìkì àti olùgbékalẹ̀ wẹ́ẹ̀bù ní ilé iṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ budding tech industey ní Nàìjíríà. Ó gbìyànjú gidigidi láti kọ́ ara rẹ̀ bí wọ́n ṣeń gbé orin jáde pẹ̀lú irinṣẹ́ fruity lóòrè tí ó sì ń gbé orin jáde lọ́fẹ̀ẹ́ ṣáájú kí ó tó pàdé CKay tí ó jẹ́ agbórinjáde Afuro jáde, ìbápàdé CKay yí ni Tempoe fi gbé orin àdákọ rẹ̀ tí pe ní "Nkechi Turnup" ní ọdún 2016[1] Bákan náà ni ó tún gbé orin CKay tí wọ́n pè ní Container oyún gbé orin Play jáde fún Blaqbonez, àwọn orin méjèèjì yín ni Chocolate City ṣe àtìlẹyìn fún. Tempoe di akẹ́kọ̀ọ́ nílé ẹ̀kọ́ agbórinjáde Sarz Production Academy kí iṣẹ́ àti ìmọ̀ rẹ̀ nípa agbórinjáde lè tẹ̀ siwájú si.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Sarz . 
  1. "New Music Ckay – Nkechi Turn Up". soundcity.tv. 30 August 2021. Retrieved 5 October 2022. 
  2. "Introducing Tempoe: The Producer Behind The Latest Chart-topping Afrobeat Records". the49thstreet.com. 20 August 2020. Retrieved 5 October 2022.