Teni (olórin)
Teni | |
---|---|
Teni ń bá Wazobia Max TV sọ̀rọ̀ ní oṣù keje ọdún 2018 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Teniola Apata[1] |
Ọjọ́ìbí | 23 December 1992 Lagos State, Nigeria |
Irú orin | Afro |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | ọdún 2016 di àkókò yìí |
Labels | Dr. Dolor Entertainment |
Associated acts |
Teniola Apata, tí a bí ní 23 Oṣù kejìlá ọdún 1992, tí a mọ̀ sí Teni, jẹ́ akọrin ati amúlúdún ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[3][4][5]
Ìgbésí ayé àti ìbẹ̀rẹ̀ orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Teni ní 23 Oṣù kejìlá ọdún 1992, ni ìpínlẹ̀ Èkó. Ó jẹ́ àbúrò olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí à ń pè ní Niniola . [6]
Ó kàwé ni lé ìwé gírámà Apata Memorial High School. Ó sì kàwé ni ilé ìwé gíga America Intercontinental University níbi tí ó ti gboyè nínú imọ ìṣàkóso ìṣòwò iṣowo. [7]
2016-2019: Fargin, Askamaya ati Awọn igbasilẹ miiran
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orin tí Teni kọ́kọ́ kọ ní "Amen" nígbà tí ó wà ní ìgbà ti Shizzi ń ṣe àkọ́so rẹ lábẹ́ rẹ́kọ́ọ̀dù "Magic Fingers Record". Ó kúrò nibẹ lọ sí Doctor Dolor ní ọdún 2017. [8]
Òkìkí rẹ bẹ̀rẹ̀ sí ní gbòòrò lẹ́yìn tí ó kọ “Fargin” ní oṣù Kẹ̀sán ọdún 2017. Ìlú sì mọ ọkà lẹ́yìn tí ó kọ "Askaya", "case" àti "Uyo meyo"
Askamaya wà ní ipò karun dínlógún ní àwọn orin ogún tí wọ́n yà sọ́tọ̀ ní MTV Base,ti ó jẹ́ orin tí wọ́n nifẹ sí jùlọ ní ọdún 2018.
Àwọn amàṣàjọ orin rẹ̀ kookan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún tí ó kọ wọ́n | Àkọlé | Alúbọ́ọ̀mù |
---|---|---|
2016 | "Amen" | Non-album single |
2017 | "Fargin" | |
2018 | "Wait" | |
"Pareke" | ||
"Lagos" | ||
"Askamaya" | ||
"Fake Jersey" | ||
"Shake Am" | ||
"Case" | ||
"Pray" | ||
"Uyo Meyo" | ||
2019 | "Party Next Door" | TBA |
"Sugar Mummy" | ||
"Power Rangers" | ||
2020 | "Marry" | Non-album single |
2021 | "For You" ft Davido | Wondaland |
2021 | "Dorime" | Non-album single |
Year | Title | Album |
2018 | "Rambo" (Dr. Dolor featuring Teni) | Non-album single |
"Pray" | ||
"Aye Kan" (Shizzi featuring Teni and Mayorkun) | ||
2019 | "Sound" (Diamond Platnumz feat. Teni) | Non-album single |
2020 | Fuji Pop (Ojayy Wright featuring Teni) | Non-album single |
Year | Title | Album |
2017 | "Like Dat" by Davido | Non-album single |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀][Ẹ̀ka:Àwọn ọmọ Yorùbá]]
- ↑ Anazia, Daniel (February 29, 2020). "Teni’s Billionaire concert at Indigo O2 Arena made London standstill". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on May 29, 2022. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ "Teni and im former label boss Shizzi do gbas-gbos ontop mata of her hit song 'Case' - BBC News Pidgin". BBC News Pidgin. December 19, 2021. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ Bassey, Ekaete (May 4, 2022). "Teni lambasts critics dictacting how to spend her money - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ Kochhar, Nazuk (18 October 2018). "Teni rules, here's the proof". The FADER. https://www.thefader.com/2018/10/18/teni-rules-askamaya-fake-jersey-african-pop.
- ↑ Olatunbosun, Yinka (26 October 2018). "Teni Makanaki's Strides to Stardom". This Day. https://www.thisdaylive.com/index.php/2018/10/26/teni-makanakis-strides-to-stardom/.
- ↑ "My love for Niniola stronger than music –Teni Entertainer" (in en-US). Punch Newspapers. https://punchng.com/my-love-for-niniola-stronger-than-music-teni-entertainer/.
- ↑ "SPOTLIGHT: My late father will be proud that his legacy is untarnished, says Teni". The Cable. https://lifestyle.thecable.ng/spotlight-teniola-the-entertainer.
- ↑ "Teni Entertainer is one of Nigeria's fastest rising musicians" (in en-US). Archived from the original on 2017-01-27. https://web.archive.org/web/20170127145508/https://www.pulse.ng/buzz/teni-entertainer-is-one-of-nigeria-s-fastest-rising-musicians-id6076858.html.