Jump to content

The Netng

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Netng
TypeOnline publication
OwnerID Africa
FounderAdekunle Ayeni
PublisherID Africa
FoundedNovember 23, 2009
HeadquartersLagos, Nigeria
Sister newspapers23Star, Neusroom, Orin
Official websitehttps://thenet.ng/

The Netng (Nigerian Entertainment Today) tí a tún mọ̀ sí NET jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ìdánilárayá lórí ẹ̀rọ-ayélujára, tó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ó jẹ́ orísun ilé-iṣẹ́ ìdánilárayá, oge-ṣíṣe, àti ìròyìn nípa ìgbésí ayé ẹ̀dá. [1][2][3] Netng ṣẹ̀dá apá kan NET Newspaper Limited (NNL) títí di ọdún 2019 nígbà tí wọ́n ID Africa gbà á. [4][5] Netng jẹ́ olùṣètò NECLive (Nigerian Entertainment Conference) èyí tó jẹ́ Àpéjọ Eré ìdárayá Nàìjíríà àti the NET Honours. [6][7][8][9]

Nigerian Entertainment Today (NET) dásílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta-lé-lógún oṣù kọkànlá ọdún 2009, nípasẹ̀ Ayeni Adekunle.[10] NET tún ṣiṣẹ́ bí iléeṣẹ́ atẹ̀wétà, ó sì ti ṣe àtẹ̀jáde tó ti kiri mẹ́ta-dín-lọ́gbọ̀n àwọn ìlú pàtàkì Nàìjíríà, ó sì ti tà tó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá lọ́sọọsẹ̀. [11] Ní ọdún 2016, NET ní díẹ̀ díẹ̀ kẹ́sẹ̀ ilé-iṣẹ́ àtẹ̀jáde rẹ̀ kúrò nílẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ọ̀pọ̀ nínú àwọn òǹkàwé wọn ti sún sí orí ẹ̀rọ ayélujára láti wá àwọn ìròyìn ìdánilárayá. Ní oṣù kẹrin ọdún 2013, ilé-iṣẹ́ ipò ojú òpó wẹ́ẹ̀bù kan, Alexa fún Netng ní ipò kẹ́ta-lé-lọ́gbọ̀n ojú òpó wẹ́ẹ̀bù tí a ṣàbẹ̀wò jùlọ ní Nàìjíríà. [12]


  1. "NETNG Executive Editor/COO Jide Taiwo Resigns". https://www.pmnewsnigeria.com/2019/08/14/netng-executive-editor-coo-jide-taiwo-resigns/. 
  2. "NETng To Announce Nominees For NET Honours on Friday". BrandCrunch Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-19. Retrieved 2020-06-02. 
  3. "BBnaija housemate's drama during a NETng interview". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-05. Archived from the original on 2021-12-20. Retrieved 2020-06-02. 
  4. "ID Africa acquires TheNETng to form marketing, media and technology powerhouse". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-04. Retrieved 2020-05-25. 
  5. OloriSupergal (30 April 2012). "Olori Supergal". Olori Supergal Blog. Retrieved 23 July 2015. 
  6. "Neclive Organizers unveils new two dah format for 2020". guardian.ng. February 2020. Archived from the original on 2023-09-25. Retrieved 2020-05-25. 
  7. "NET Honours 2019 unveils nominees". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-14. Retrieved 2020-05-25. 
  8. "NET Honours Is Back, Winners To Be Revealed At NECLive 2019". BrandCrunch Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-05. Retrieved 2020-05-25. 
  9. "NET Honours 2019: Here are the nominees | Encomium Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 April 2019. Retrieved 2020-05-25. 
  10. Olori Supergal (26 April 2012). "NET Publisher Shares Success Story". [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  11. "About NET - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Number 1 Entertainment Daily". Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Number 1 Entertainment Daily. 26 February 2015. Retrieved 23 July 2015. 
  12. "thenet.ng Site Overview". alexa.com. Archived from the original on 13 September 2015. Retrieved 23 July 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)