Jump to content

The Wedding Party (Fíìmù 2016)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti The wedding party)
The Wedding Party
AdaríKemi Adetiba
Àwọn òṣèré
Orin
  • Dr. Bayo Adepetun
  • Michael "Truth" Ogunlade
Ìyàwòrán sinimáAkpe Ododoru
OlóòtúAndrew Webber
Ilé-iṣẹ́ fíìmùEbonylife Films
FilmOne
Inkblot Production
Koga Studios
OlùpínFilmOne Distributions
Déètì àgbéjáde
  • 8 Oṣù Kẹ̀sán 2016 (2016-09-08) (TIFF)
  • 26 Oṣù Kọkànlá 2016 (2016-11-26) (Lagos)
  • 16 Oṣù Kejìlá 2016 (2016-12-16) (Nigeria)
[1]
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish
Yoruba
Igbo
Ìnáwó₦60 million[2]
Owó àrígbàwọlé₦453,000,000[3]

The Wedding Party jẹ́ fíìmù àgbéléwò apanilẹ́rìn-ín àti ajẹmọ́fẹ̀ẹ́ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde lọ́dún-un 2016 tí Kemi Adetibasì jẹ́ olùdarí fíìmù náà. Àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án ọdún 2016 ní Toronto International Film FestivalCanada àti lọ́jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún kan náà ní Èkó hotel and suites ní Èkó. Agbẹ́jáde fíìmù náà lágbàáyé wáyé lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejìlá ọdún 2016 tí ó sì jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí àwọn èèyàn ń wò jù.[4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "The Wedding Party". Archived from the original on 19 August 2016. Retrieved 19 August 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "LONG READ: How The Wedding Party became the biggest critical and commercial Nollywood success story". 31 December 2016. 
  3. "The Inflection Point Of Nigerian Cinema?". 15 May 2019. 
  4. Vourlias, Christopher (2017-02-04). "'Wedding Party' Fuels Record Nigerian Box Office Despite Ailing Economy". Variety (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-05. 
  5. "'Wedding Party 1' named highest-grossing Nollywood movie of the decade2 minutes read". News Central - Latest in Politics, Business, Sports and stories across Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-09. Retrieved 2020-10-05.