Timbuktu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Timbuktu

Tumbutu
City
  transcription(s)
 • Koyra Chiini:Tumbutu
Sankore Mosque in Timbuktu
Sankore Mosque in Timbuktu
Country Mali
RegionTombouctou Region
CercleTimbuktu Cercle
Settled10th century
Elevation
261 m (856 ft)
Population
 (1998[1])
 • Total31,973

Timbuktu (Timbuctoo) (Koyra Chiini: Tumbutu; Faransé: Tombouctou) je ilu ni Agbegbe Tombouctou, ni orile-ede Mali ni Iwoorun Afrika. O je gbigbega nigba ijoba mansa kewa ni Ile Obaluaye Mali, eyun Mansa Musa. Ibe ni Yunifasiti Sankore ati awon madrasas miran wa, bakanna ibe ni o je gbongan oye ati oro emin to yun je ibi ti imale ti fon kakiri ni Afrika ni orundun 15th ati orundun 16th. Awon mosalasi ninla meta ibe, Djingareyber, Sankore ati Sidi Yahya, je lati atijo. Botilejepe won je titunse ni gbogbo igba, awon oso yi ni ewu sisodiasale.[2]
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]